Home / Àṣà Oòduà / Odu Ifa Oturupon Meji/ Ologbon Meji

Odu Ifa Oturupon Meji/ Ologbon Meji

| | | |
| | | |
 |    |
| | | |

Ekaale  eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise oni o, esu odara yio gbare ibunkun lopolopo fun wa loni o ase.
Odu ifa OTURUPON MEJI/OLOGBON MEJI lo gate laaro yi, ifa yi gba akapo ti odu ifa yi ba jade si niyanju wipe ki o bo esu odara daradara ki esu baa le sina owo nla fun, ki esu baa le so di olowo, oloro ati eniyan Pataki lawujo.
Ifa naa ki bayi wipe:
Omi kunkunkun Omi fa Oko oya ya okun ko tie mi legbelegbe sihin, okun ko tie mi legbelegbe sohun bi orogun eni bani ina sile tiyawo re ki jo a difa fun orunmila baba nlo toro iwa lowo Labupee won ni ki o karale ebo ni ki o wa se, (obi meji……..igba ewe ayajo ifa) Orunmila kabomora orunmila rubo esu wa pese aje nla fun baba orunmila wa dolowo o dolokun o donide o wa njo o nyo o nyin awo awon awo nyin ifa, ifa nyin eledumare.
Orunmila wa fiyere ohun bonu wipe;
Nje tani lowo a una lode? Esu odara oun lo lowo a una lode esu odara.
Eyin eniyan mi, mo gbaladura laaro yi wipe eledumare yio pese owo nla eleyi ti nderu nba osi funwa, ibikibi ti ire aje tiwa ba wa lode ilu yi esu yio jeki o towa wa, esu koni dina ire aje wa, yio lana funwa ti ire owo nla naa yio fi de ni kiakia pelu irorun ni o aaaseee.
ABORU ABOYE OOO.

 

English Version:

Good evening my people,
How was your day? Hope it was great, May esu bring abundant blessings for us today ase.
It is OTURUPON MEJI/OLOGBON MEJI corpus that revealed this morning, ifa advised whoever this corpus revealed out for that he/she should feed esu odara very well so that he(esu) may provide an abundant money for him/her and he/she may become successful in life.
Hear what the Corpus said:
Omi kunkunkun Omi fa Oko oya ya okun ko tie mi legbelegbe sihin, okun ko tie mi legbelegbe sohun bi orogun eni bani ina sile tiyawo re ki jo it cast divined for Orunmila when father was going to borrow money from Labupee, he was advised to offer sacrifice, (two………and ifa leaves) and he complied, aftermath Labupee provide for him plentifully. Orunmila became greatly rich he started dancing and rejoicing praising priest the priests were praising ifa while ifa was praising God.
He started singing the song of ifa that;
Who is the owner of the money we are spending on the earth? esu odara! It is the one that owns the money we are spending on the earth, esu odara!.
My people, I pray this morning that wherever our own money is on the earth it will locate us today, God will provide us a big money that use to scared wretchedness today, esu odara will make a good path for us so that the money may reach us easily and quickly amen.

 

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...