Home / Àṣà Oòduà / What Ifa Says in Ogbe Ate

What Ifa Says in Ogbe Ate

In Ogbe Ate, Ifa says everybody should do Itefa (Ifa initiation) to know one’s mission on earth, one’s destiny and in order to have all good things of life.

A ki i ji ni kutukutu/ Ka ma modu to dani saye/ Dia fun Olupo Alaelu/ Eyi ti i feyin ti/ To n fekun se-rahun ire gbogbo/ Eyi tile aye ni lara koko bi ota/ Won ni ebo ni ko se/ Ko si lo re e tefa/ O gbebo o rubo/ Ko pe ko jinna/ Ire gbogbo wa yade tuuru tuuru/ Ifa de Alase/ Ope Abise wara,

It is not good for one to start life/ Without knowing the Odu that brought one to the world/ Di-vined for Olupo Alaelu/ Who worried/ And crying for his inability to be successful in life/ Not get-ting all goods of life/ His life was too hard for comfort/ He was advised to offer sacrifice/ And to do Ifa initiation/ He complied/ Before long/ All good things of life became his lots/ Ifa the embodiment of Ase is there/ Ope which predictions must come to pass.
Blessings of Irunmole on all. Baba Olosun.

About oodua

9 comments

  1. Iba oo Agba Awo….ajepe aiye oo BABA.

  2. E ku oke gun baba. Ifa a fa rere fun wa. Ase oo.

  3. ogbe ate. akuko to ko loru ana iko rere loko.Erin ji ohun sokun ailola efon ji ohun sokun ainiyi.Isin ji ohun sokun aila.Woni ki won karanle ebo ni ki won se.Erin ji erin nfola mi.Efon ji ohun gbayi labata. oju kii pon isin aimala.ebo afin baba

  4. OGBE ATE:- Ekikanna mi ni mo fi njeran, eriki mi ni mo fi njobi, eriki mi o ba wa jobi tan ki o to wa mu otin si, adifa fun oba efon alaye ekiti nigba ti nfi omije sebere ire gbogbo, ebo lo ni ki o ma se, riru ebo titu ope, alaye di oloro odi oniregbogbo. Ijo nijo ayo niyo, onyin awo, awo nyin ifa,ifa nyin eledumare. Aboru boye ooo baba

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ifa

Kùtùkùtù Ìrèní Laó He Erè Nígbódù Oòni

Òní laó roko létí opónÒla laó sákà lágbèrùKùtùkùtù ìrèní laó he erè nígbódù oòniKáyáa múlé pontíKámú òdèdè rokàKáfi agbada dínranÀwèje wèmu nípón omodé wòyí lójúÒrìsà lópabuké tánLódákún sábaro nídìíOmo-ojo húnsáré gíríjo-gíríjoOmo-ojo húnsáré gìrìjo-gìrìjoIlé-ifón kògba obàtáláÈlàgboro kògba òrìsàOjúgboro ni tàfínÈlàgboro ni tòrìsàOmi níti ojú-omi rúwáÈròyà wáàponÈròyà wáàmuRúkú-rùkù-rúkú niwón nse lókè ohùnkòErú kùnrin won nííjé bánakúErú bìnrin won nííjé wòrúkúDimúdimù aleìgbòOkùnrin yàkàwú orí ìgbáÌgbá kòwóOkùnrin yàkàwú kòsòkalèÒní laóko igbó olú-kóókó-bojoÒla laóko igbó olú-kóókó-bojoAkogbó olú-kóókó-bojo tánApa ekùn kan mìnììjò-miniijo tínbe lábé ìtíWónní kí ...