Home / Àṣà Oòduà / Ogo Omu-Aran Ni Ipinle Kwara Pe Eni Odun Mokanlelogota (61)

Ogo Omu-Aran Ni Ipinle Kwara Pe Eni Odun Mokanlelogota (61)


Oni, 27-09-2015, ni Bisoobu Dafiidi Olaniyi Oyedepo pe eni odun mokanlelogota (61). Omo bibi Omu Aran ni ipinle Kwara ni i se, oun kan naa ni oluso aguntan agba fun ijo Living Faith Ministry to kari aye pata. Onkowe ni, olukoni oro Olorun ti okiki re kan kari aye ni, bakan naa lo tun je oludasile ile iwe. A ba olojo ibi yo lonii, a si gbadura wi pe Olorun yoo so agbara Bisoobu dotun. Igba odun, o dun kan ni.

 

Source: olayemioniroyin.com

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Bishop Oyedepo ní láti tẹ̀lé òfin tàbí kí ó dá orílèèdè tirẹ̀ sílẹ̀ – Iléesẹ́ Ààrẹ

Oludasile ile ijosinLiving Faith Church Worldwide, Bishop David Oyedepo lo ti n gbe peregi kana pelu ijoba apapo lati bii odun meloo kan seyin. Ofin lori owo ori ati amojuto awon ile-ise ati awon ile-ijosin ti ajo Company and Allied Matters Acts (CAMA) maa samojuto gege bi ijoba apapo se sagbekale re lo fa gbonmi-sii-omi- o too ti ote yii. Bishop Oyedepo ni eyinju Olorun ni ile-ijosin, ko letoo sii ki enikeni fowo kan an. O ni oro ile-ijosin da ...