Home / Àṣà Oòduà / Olorì Basirat tí ó pé odún mókàndínlógún ni ojó mélòó séyìn ya àwon àwòrán tí ó wuyì.

Olorì Basirat tí ó pé odún mókàndínlógún ni ojó mélòó séyìn ya àwon àwòrán tí ó wuyì.

Olorì oba àti ìyá ìbejì ni a gbó wípé ó máa n dá oba lóhùn láàfin àti wípé òhun ni ó máa n pèsè gbogbo nkan tí Kábìèsí fé láàfin àti ní orí èro ayélujára.
A gbó wípé kò sí ibi náà tí e ó ti ri Aláàfin tí e kò ni ri Olorì Ola níbè.
Olorì ti se ayeye ojo ìbí rè ní àrà òtò látàrí pínpín àwòrán tó yááyì.

About Awo

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...