Home / Àṣà Oòduà / Omoba Eze Madumere àti Chioma Rosemary kí omobìnrin kú àbò.

Omoba Eze Madumere àti Chioma Rosemary kí omobìnrin kú àbò.

    Igbékejì Gómìnà ìpínlè Imo , Omoba Eze Madumere àti aya tí ó sèsè fé, Omoba Chioma Rosemary Madumere kí omobìnrin káàbò léyìn osù méjì léyìn ìgbéyàwó, won ti bí omobìnrin. Igbékejì Gómìnà ni ó pín àwòrán yí tí ó sì se àdúrà fún omo tí ó rewà yí ní orí èro ayélujára( Facebook).

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo