Home / Àṣà Oòduà / Igbo pàdé calabar, àwòrán kí won tó se ìgbéyàwó bí okùnrin náà se fi owó kó ìdí arábìnrin náà.

Igbo pàdé calabar, àwòrán kí won tó se ìgbéyàwó bí okùnrin náà se fi owó kó ìdí arábìnrin náà.

Àwòrán èyí kí ó tó di ojó ìgbéyàwó ti arákùnrin Igbo tí a mò sí Ofor, tí ó ti se tán láti fé aya àfésónà rè Witney tí ó jé Calabar ní ojó etì, ojó kejìdínlógún osù kokànlá odún yí (18/11/2017).

Oko tí ojú rè ti wà lónà ní láti gbá ìdí ìyàwó rè mú, èyí fi hàn wípé okùnrin yí ti to ara rè sí okùnrin àkókó nínú ayé obìnrin yí.

A ki yí tokotaya tí ó n bò lónà .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo