Home / Àṣà Oòduà / Omokùnrin Wizkid , Ayo kékeré òun àti ìyá rè múra jáde nínú aso orílé èdè Nàíjíríà .

Omokùnrin Wizkid , Ayo kékeré òun àti ìyá rè múra jáde nínú aso orílé èdè Nàíjíríà .

    Binta Diallo àti omokùrin rè ,king Ayo kékeré jáde lo láìpé tí won sì tàn gan nínú Dashiki won àti aso orílè èdè Nàíjíríà. Aso orílè èdè Nàíjíríà yí jé kí ó dà bi omo Yorùbá tí ó gba okàn obìnrin kan ….

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...