Olùsó àgùntàn èké kan tí a mò sí Osinachi Christopher láti ìpínlè Abia ni won fi s’èsín léyìn ìgbà tí owó ti tèé nígbà tí ó ń gbìyànjú à ti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé ní agbègbè Nnobi ní ìpínlè Anambra . Gégé bí eni tí ó pin se so èyí kó ni àkókó tí Olùsó àgùntàn náà ma se èyí.
Ka ohun tí Uzochukwu Onuabuchi so ní ojó etì tí ó kojá, ojó ketàlélógún osù kefà (Friday, June 23rd)
Ojú kò kú ní yé rí, ìyanu kò sì le dópin .Olùsó àgùntàn Osinachi Christopher rè é láti Isuochi ní ìpínlè Anambra, owó tè é nígbà tí ó fé ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé, tí won ma padà gbé jáde l’órúko ìdílé náà, ó tún jéwó wípé sisé pèlú Olùsó àgùntàn kan tí orúko rè ńjé Miracle Ihuoma.
Ó tún jéwó wípé. Olùsó àgùntàn èké Miracle ri ohun tí a kò mò sí iwájú ìsò Alabi kan tí ó jé ìyàwó Makosa. Olùsó àgùntàn yí tún wá so fún arabìnrin yí wípé Olùsó àgùntàn ti télè Ebubedike ni ó ri ohun náà síbè. Ònà èké yí ni ó gbà láti lé Ebubedike lo. Ebubedike tí olórun ti ń lò fún isé ìyanu ní Nnobi.
Ohun kan tí èmi mò láyé ni pé kò sí ohun tí ó pamó lábé òrun. Olórun ti fi Olùsó àgùntàn èké Miracle Ihuoma hàn , tí ó ní Ìjo ní Makosa ní Ifite Nnobi ní ìpínlè Anambra.
Gégé bí Olùsó àgùntàn èké Osinachi nínú àwòrán àti Miracle Ihuoma. Ó seoooooo ……
Continue after the page break for English version