Home / Àṣà Oòduà / Sisi ologe elo ni Suru ooo

Sisi ologe elo ni Suru ooo

Se Eledumare to da IDI yin bi o se mon IDI kaluku yin se ko se da ni in? Awon kan wa sese ma lo ogun abi abere. Se ni tori iranu yi na
E wo won oooo. Awon kan ni IDI won ti baje yi ooooo Latara pe won tu ise Eledumare wo. Ko ye won ni in pe ise Eledumare kose tuwo laye. E ma bara yin laye je ni ooooo
Fi idi e sile bi Eledumare se da yen. Ema tori oge o si ba rayin laye je ooo
Amoran mi fun gbogbo eyin alaseju ti nkan ti Eledumare se funyin o jo yin loju. Seri bi awon se ba IDI je. Ki Eledumare sanu wani ooo

About BalogunAdesina

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...