Home / Àṣà Oòduà / Tobi Bakre ya àwòrán pèlú Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka.

Tobi Bakre ya àwòrán pèlú Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka.

Ará ilé BBNaija télè tí ó sì jé àyànfé òpò ènìyàn tí a mò sí Tobi Bakre lo sì orí èro ayélujára rè tí ó n jé Insítágírámù láti pín àwòrán òhun àti àwon ènîyàn pàtàkì bíi Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka ní ibi ìdíje eni tí yóò jé olómoge àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.
E wo àwòrán òun pèlú Ebuka àti Bovi.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo