Home / Àṣà Oòduà / Goodluck Ebele Jonathan se ayeye odún mókànlélógóta (61) ojó ìbí rè ní èní.

Goodluck Ebele Jonathan se ayeye odún mókànlélógóta (61) ojó ìbí rè ní èní.

Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan GCFR GCON tí won bí ní ogún’jó osù Belu ní odún 1957, tí ó jé olósèlú ní orílè èdè Nìjíríà tí ó sì sin ìlú gégé bíi Ààre orílè èdè Nìjíríà láti odún 2010-2015. Kí ó tó di wípé ó di Ààre ó ti kókó sìnlú gégé bíi Igbákejì Ààre orílè èdè yí ní odún 2007 di 2010 àti gégé bíi Gómìnà Ìpínlè Bayelsa láti odún 2005 di odún 2007.
Ó pàdánù ìdíjé fún Ààre orílè èdè Nìjíríà ní odún 2015 tí Ààre Muhammad Buhari sì gbégbá orókè, òun ni Ààre àkókó tí ó wà lórì oyè tí ó sì tún pàdánù ìbò.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo