Temitope Osoba tí gbogbo ènìyàn mò sí Tope Osoba jé òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó sì tún jé olùko eré, won bí i ní ojó kejì osù kejìlá, odún 1985.
Ó jé jé akékòó jáde ilé-èkó gíga ifáfitì Olabisi Onabanjo tí ó kó nípa èkó káràkárà.
Òsèré tí ó rewà yí bèrè eré orí ìtàgé ní odún 2005 nígbà tí ó kópa fún ìgbà àkókó nínú eré tí a mò sí “Ijoya” láti owó Laide Bakare.
Ó di gbajúgbajà òsèré ní odún 2009 nígbà tí ó kópa nínú “ogun mi” láti owó Dayo Amusan . Báyìí ó ti hàn nínú eré tí ó kojá ogún bí apeere, Abimbola, Anu oju mi láti owó Adesanya, Omotara Johnson, Gucci girl àti béè béè lo.
Ó se ayeye ojó ìbí rè pèlú àwon àwòrán tí ó ta lénu nígbà tí ó pé odún métàlélégbòn.
Home / Àṣà Oòduà / Tope Osoba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún métàlélógbò (33) pèlú àwon àwòyanu àwòrán.
Tagged with: Àṣà Yorùbá