Home / Author Archives: Admin Manager (page 238)

Author Archives: Admin Manager

Ori mi gbere ko mi loni o…

Orí. Kò sí òòṣà tí í dá ni í gbè lẹ́hìn orí ẹni. Orí là bá bọ, à bá fòrìṣà sílẹ̀. Ori mi gbere ko mi loni o..

Read More »

Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀ Ẹnu lẹbọ.

Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀ Ẹnu lẹbọ. Kí là ń bọ nÍfẹ̀? Ẹnu wọ̀n Ẹnu wọn là ń bọ nÍfẹ̀ Ẹnu wọn. Kí ẹnu mi má kó bá mi o Olúbọ̀bọ̀tiribọ̀ The mouth is an altar of worship. What is it that we worship ...

Read More »

Bawo ni ase le ko nipa odu ifa erindinlogun.

Olotu, Bawo ni ase le ko nipa odu ifa erindinlogun.

Read More »

Iwure Eyonu Awon Agba

Edumare,Oba Ajiki,Ajige,Oba toto bi aro. Awa dupe lowo re ,pe o yo nu si wa lati atete ko se titi di oni oloni. Jowo Baba Alanu ,masai ko Anu re kuro Lori wa (mi). Jowo Baba ologo lola ,je ki ...

Read More »

Tani oma yin logo ti oba ji?

1.Eledumare 2.Mohamedi 3.Jesu 4. Satani Sojunu ti oba ji

Read More »

E dakun eba wa fun Ogbeni yi ni oruko kan

Read More »

Oruko wo leyin npe oko yi ladugbo tiyin ?

laba tia agbegi ma gbeyawo

Read More »

Kini Won Npe Iru oko yi ni ede Tire ?

Read More »

E bami Dasi Oro yi Eyin elegbe mi…

  Ninu Obi Eni tabi A’ya Eni, ewo lose pataki ?

Read More »

Aje olokun yo fiso sile gbogbo wa ooo

AJÉ Iwọ́nrín Olókun a bi ara á ‘le koko bí ọta, Òhun l’ó d’ifa fún orí Àpéré ọ̀nà ọmọ a t’Àkàrà ṣ’ọlà.. (Ajé brings prosperity. I wish all Ifa University members a prosperous Ifa year. )Aṣẹ.

Read More »