Ni ojo Aje to koja yii (29/02/15) ni awon ajinigbe kan yawo ileewe Babington Macaulay Junior Seminary School to kale si agbegbe Ikorodu nipinle Eko ti won si ji awon omo obirin akekoo meta salo raurau. Gege bi alaye ti ...
Read More »Awon ojogbon fi oye dokita da Tinubu lola
Oloye agba egbe APC, Asiwaju Ahamed Bola Tinubu ni won ti foye dokita dalola bayii ni ogba Yunifasiti tiluu Abuja. Idalola agba oloselu to je gomina ti yoo je sikejila (12th) nipinle Eko lo waye ninu ayeye ikojade awon akekoo ...
Read More »Rogbodiyan Mile 12: “Won ja omo ikoko gba lowo mi” – Abiyamo
Leyin rogbodiyan to be sile ni agbegbe Mile 12 to wa niluu Eko l’Ojobo ose to koja yii (03/03/16), okunrin kan ti oruko re n je Daniel Igba lo ti ke gbajari sita wi pe, awon kan ja omo gba ...
Read More »E fun irun yi loruko ?
Ipo wo ni iwo fe wa ninu awon olowo ile Afirika?
Ni owuro yii, mo fi akoko mi sile lati ka nipa aseyori Mike Adenuga, alase ati oludari ile ise ibanisoro Gbobacom. Ohun to ta mi kan ko ju iroyin tuntun nipa re eleyii to n se afihan re gege bi ...
Read More »Omo odun metadinlogun (17) joba nile Naijiria
*Isele naa farape ti Awujale tile Ijebu Oba Sikiru Adetona, Awujale tile Ijebu, eni ti won bi lojo kewaa osu karun-un odun 1934 gori ite awon baba re lojo keji osu kerin odun 1960 leni odun merindinlogbon (26), eleyii ti ...
Read More »Ogoji (40) eniyan n ja raburabu fun ipo gomina nipinle Ondo
Awon eniyan bi ogoji (40) lapapo ni won ti fi ife han bayii lati dije fun ipo gomina ipinle Ondo eleyii ti yoo waye ninu odun yii. Ninu egbe oselu All Progressives Congress (APC), ogbon eniyan ni won ti nawo ...
Read More »Jegudujera: EFCC tun ti gbe ebi Alison-Madueke niluu Abuja
Awon Yooba bo, won ni tina ko ba tan laso, eje ki i tan leekanna. Awon ajo ti n gbogun ti iwa jegudujera ati sise owo ilu mokunmokun, EFCC, ti gbe arakunrin Donald Chidi Amamgbo to je okan lara ebi ...
Read More »Olajumoke omo oniburedi
Opolopo ni i pokiki Olajumoke Orisaguna omo oniburedi gege bi oloriire ti Edumare da lola ojiji pelu bo se se alabapada agbaoje ayaworan ati olorin ti n je TY Bello. Laaarin iseju kan, omo oniburedi di orekelewa oba onise oge. ...
Read More »Igbeyawo Ooni Ile-Ife fo yangayanga?
*Oba Ogunwusi n mura lati se igbeyawo tuntun Lose to koja ni awon aheso oro kan be sile nigboro eleyii to ti bere si ni mu awuyewuye lowo bayii. Lara awon oro naa ni eyi ti n wi pe, ...
Read More »