

Mo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹBí ẹ bá rí ikàn l’ọ́jà kí ẹ ma rà fún miMo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹAtẹ̀gbẹ̀ tí o bá délé Olódùmarè kí o ra ọmọ wẹrẹ wá fún miA dífá fún Àbẹ̀kẹ́ tí ń se eléwùrà l’ọ́jà tí n se elépo ní imọdẹ àgàn òde àpàẸkún ọmọ lo n sunÒun le bímo lópòlopò ni ndafa síẸbọ lawo ni kóseKò sí ohun tó wuyì ju ọmọ lọỌmọ làdèlé ẹniKò ...