Home / Blog Pagepage 102

Blog Page

Ejowo eni to ba mo olorin yi ko ko oruko re

Edakun kini oruko olorin yii

Read More »

Gbogbo wa ni o bo ikin la! Aase!

IFA NI Asese roko agbe adabi akiti ohun obo Adifafun Ajala yobo Ikin la lese oke ebo won ni kose ogbebo ni be osebo bi kasai bokinla olowo Ajala bi kasai bo Ikinla emin ateyin ololufemi gbogbo wa labo ikin ...

Read More »

Awo Ori – Odu Odi Meji

Odidi kirimu kirimu, Awo Ori A difa fun Ori Ori n be logbere oun nikan Ebo won ni kowa se O gbebo nibe O rubo Kerekere Oju wa, Eti wa, Imu wa, Enu wa Gbogbo won wa ba Ori duro ...

Read More »

Ogulutu Oro Toni – 09.07.2016

Hummmmmmmm igbiyanju lagbe ngba Olohun lomu isu ta ‪#‎woo_orewa‬ Nje o mo pe eni tio sun(sleep) lo nsun(move)????? ??? Gbiyanju lati tesiwaju loni majeki ijakule re fao seyin nigbesi aiye re ‪#‎gbomi_dada‬ Koseni tio ni ‪#‎sugbon‬ tie gboju re kuro ...

Read More »

Akara Imora’n toni – 09.07.2016

*Emi ko ni ku saaju ojo ayo mi.*Emi ko ni fi ewon logba.*Iji aye ko ni gbe mi lo(Ase Edumare). …………. ‪#‎AKARA_IMORAN‬ : Gbiyanju lati ni iwe iranti fun awon olooore re; ki o si gbiyanju lati fa iwe asise ...

Read More »

Gbogbo Ile e ma binu simi ooo

Oro buruku pelerin erin’kkkkkk Mo sese ri eran ewure ni ibi to pokunso so ni in Eran ti moni ki a fe se odun lo pokunso yi ooo Mi o mon nkan to nba leru o erin’kkkkkk

Read More »

IYA wa Bukky Ajayi sun re oooooo

Bi oro aye se ri ni yen oooo Bi poopo sin-sin odun se wa nta. Olodumare ti se bi o se nse fun awon ebi iya wa Bukky Ajayi Iya ti lo ni aro yi o. Gbogbo eyin Omo Ooduarere o ...

Read More »

Tani Onife Si Julo Ninu Awon Osere Meji Yi ?

Read More »

Orunmila o jiire loni oooooo!

Oluwo Agbaye; Olori Awo Ode Isalaye; Ifa a mo oni mo ola bi Oba Olodumare; Igba eran ni a fi i bo’Fa; Aboruboye! Aboyeboru! Aboyebosise! cc- Yeyelufe IyaOgbe OmoEdu Oyewole

Read More »

Idile Alayo – Odun ikerin ree ti mo ti se igbeyawo sugbon…

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. ...

Read More »