Home / Blog Pagepage 78

Blog Page

Ònà tí èèyàn le gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin. (Ways To Deal With An Introverted Wife)

Tí ènìyàn bá wà lábé òrùlé kan náà, ó ye kí won kókó gbà pé ìwà wa kò le b’ára wa mu. Nígbà kan náà o kò ní láti yí enìkejì padà kí o sì jé oníyè ara re. Kódà ...

Read More »

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje àjòdún Washington DC jollof.

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigeria jollof rice) ti kéde gégé bi ipò àkókó nínú ìdíje àjòdún Washington DC jollof. Ní ojó kejì osù keje odún 2017(july 2, 2017) omidan Atinuke Ogunsalu ti Queensway Restaurant &catering in Maryland US, ti se ipò ...

Read More »

Ìbon pa àwon adigunjalè méta tí ìbon bá láti owó àwon òsìsé ìdábòbò (Task force) nígbà tí owó bà wón ní Benue.

Òdómokùnrin méta kan ni owó àwon civilian Joint Task Force Nígbà tí won jalè lówó ní Jato Aka ní ìpínlè Benue tí won pa wón ní bíi agogo méjì òwúrò òní (2am). Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè náà, ...

Read More »

Ta Ni Elújoba?

Elújoba ni gíwa tí ó kúrò Lóríi oyè gégé bíi alásé oau Láìpé yìí Tí gbogbo ènìyàn sì n kan sárá sí òjògbòn náà kìí kúkú se pé wón n déédé kan sáárá sí Baba Ìwà rere àti òótó inú ...

Read More »

Àwon òrìsà tí e kò mò (sùgbón tí ó ye kí á mò) {Some Orisa you probably don’t know (But you have to)}

   Òrìsà Bayani.  Òrìsà alágbára yí ni òrìsà omodé tí a bí pèlú dàda . Ó dára kí a ma bo òrìsà yí kí á sì ma bèèrè fún ìdábòbò, kí á b’orí òtá àti gbogbo ire ilé ayé. Gbogbo ...

Read More »

Àsírí sèsè tú sí won lówó wípé ilé-isé mi ní iye owó tí ó tó Dólà lónà ogóòrun Mílíònù ($100 million) -D’banj.

Kokomaster tí a tún mò sí D’banj le sèsè di òsèré tí ó lówó jù ní ilè adúláwò (Africa). Olórin tí ó sì jé baba omo kan sèsè gbe sí orí èro ayélujàra (instagram) rè pé Cream platform tí ó ...

Read More »

Gáàsì bú gbàmù ní Cross river tí ó sì pa èèyàn méji, tí ó fa ìpalára fún àwon mérin nínú ebí.

Àwon omo ebí mérin ti igbákejì adarí kíko eré ìdárayá ní orílè èdè Nàìjíríà ” Vice President of Sport Association (SWAN), Eddie Bekom tí a gbà sí ilé-ìwòsàn léyìn ìgbà tí gáàsì tí wón fi ń dáná bú gbàmù láti ...

Read More »

Yakubu Gowon lo kí Shehu Shagari. 

Olórí ìpínlè télè (former head of state) General Yakubu Gowon lo kí Ààre ti télè Shehu Shagari ní ilé rè ní Sokoto. Gómìnà Tambuwal sìn-ín lo pèlú Olórí àlùfáà Ìjo Catholic ti Sokoto,  Bishop Matthew Hassan kukan àti àwon ènìyàn ...

Read More »

Annie Idibia da padà fún olùtèlé rè tí ó pè é ní omobìnrin tó “wor wor “.

Annie Idibia fi àwòrán yí sí orí èro ayélujàra rè (instagram) tí ó rò wípé kò rewà  pè é ní omobìnrin tó ” wor wor ” . Ìyá omo méji tí òhun náà sì da padà fun pé :bí ìyá ...

Read More »

Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).

Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè ...

Read More »