Home / Blog Pagepage 82

Blog Page

Ìdí Tí Ó Fà Á Tí Mi Ò Ní Fi Lo Káàdì Ìrántí (Memory Card) Láyémi Mó. 

Ìdí méji pàtàkì tí mi ò fi lo káàdì ìrántí (SD card) mó. SD card tí a mò sí káàdì ìrántí (memory card) tí a tún mò sí káàdì ìrántí ìtá “external memory “,ní tòótó ó jé ohun tí ó ...

Read More »

Okò Ńlá Tí Ó Kérù Ta Òkìtì Ní Òpópónà Ojúelégbà Ní Ìlú Èkó Látàrí Àìmu Bírèkì. 

Lagos response unit LRU tí a mò sí ìgbìmò ìdálóhùn wá ònà láti gbé okò ńlá tí ó kó yoyo tí ó ta òkìtì látàrí àìmu bírèkì ní òpópónà ojúelégbà, lónà pápá  bóòsì dúró (Stadium bus/stop) kúrò. LRU gbé okò ...

Read More »

Ní Iwájú Si : Nípa Ìlànà Oba Ifá Ti Gúúsù America (South America).

Àrídájú ti so wípé… 1. Àwon ènìyàn kan wà tí won ń lo orúko àti ipò Aláàfin láti fi lu àwon tí kò mò nípa Àsà yorùba ní jìbìtì ní ìlú òyìnbó. 2. Àwon babaláwo tí ó wà lábé ilé-ifá ...

Read More »

Fatai Owoseni sàkóso lílo bíbò ní Ikorodu láti owó omo oòduà rere !

Kàyééfi ńlá gbáà ni súnkere fàkere okò tí ó selè ní ìròlé àná ní bóòsì dúró Agric (Agric bus stop), Ikorodu ní ìlú Èkó. Tí ó kan ògá pátápátá ilé-isé olóòpá (commissioner of police) Ògbéni Fatai Owoseni láti yo òpòlopò ...

Read More »

Bómbù Déru Bà Wón Ní Ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond Bank) Ní Ìlú Jos

Bómbù déru bà wón ní ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond bank) ní ìlú Jos, Bí won se fura wípé wón ti wà okò kan gúnlè tí irinsé olóró Bómbù sì wà ní inú rè.  Gbogbo òsìsé ilé-ìfowópamó Diamond ti eka Katako, ní ...

Read More »

Àwòrán Kí Ó Tó Di Ojó Ìgbeyàwó Láàrin Eléyàmeyà

Omo Ooduarere tún gbé tuntun dé ooo, àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó láàrin eléyàmeyà. Femi (yorùba) àti Mma rè tí ó ń jé OGECHI láti (River), inú won dùn púpò gan bí won se ya àwòrán papò nínu aso ...

Read More »

Iná gbé arabìnrin kan tí ó jé akékòó ifáfitì ní ìjoba ìpínlè River (River state university). 

Akékòó ifáfitì ní Ìjoba ìpínlè River kan tí a ò tíì mo eye to ó su ú ni Iná gbé ní ojó ìségun (Tuesday) ojó ketàlá osù kefà (June 13). A bá a tí ó subú lulè léègbé kan tí ...

Read More »

Tonto Dikeh Pèlú Muhammed Lai Nínú Okò Ojú Òfurunfú 

Gbajúgbajà òsèré Tonto Dikeh àti Asàkóso ìwí àti Àsà (minister of information and culture) Muhammed Lai. Ya àwòrán nínu okò ojú òfurunfú nínu ipò tí ó wà ní ìsàlè. “mo wo bí ayò mi se kún tó nígba tí Hon. ...

Read More »

Ewi Toni: Toju Iwa Re Ore Mi 

Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia, Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola. Okun l’ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ...

Read More »

Owó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní darandaran ní ìlú Edo 

NAN, Otaru ti ilè Auchi, Alhaji Aliru H. Momoh , ní ìlú Edo, ti kéde ní ojó ajé bí owó se te okòó lé mérin( 24) àwon afurasí Boko Haram tí won ń se bíi fúlàní darandaran ní agbègbè náà ...

Read More »