Home / Àṣà Oòduà / Gbenga Ojoyido n jaye bi oba Lamidi niluu Amerika

Gbenga Ojoyido n jaye bi oba Lamidi niluu Amerika

Won ti so mi lenu, idi ni yii ti mo fi pinnu lati dake. Won ti fabuku kan mi, idi ni yii ti mo fi senu mi ni deede sibi.

Awon kan tile leri wi pe maa kandin ninu iyo, mo ba kuku karibonu bi eni wi pe mi o ri nnkankan.

Lati mo nipa eni ti n je Gbenga Ojoyido, ati wahala to mu oniroyin so takada iroyin nu, linki isale yiii ni alaye naa wa.

Walahi! Oro po ninu iwe kobo.
www.olayemioniroyin.com/2014/05/wahala-ti-sele-ooo-okan-ninu-awon-omo.html?m=0

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òyèkú bìwòrì

Òyèkú bìwòrì,Gbóró,gbóró,gìdì ? òyèkú b’ìwòrì?Ajan gbóró gìdìAdífáfún lájosìnOmo ab’oya ríreÈyí tio bo òrìsà obìnrin làÈròpo àti tòfàB’ifá bá..bíni níbèOya ni ko maa bo ~Translation ~ Òyèkú bìwòrìGbóró gbóró gìdìAjan gbóró gìdìCast ifá for lájosìnThe one that worship oya with blessingsThe one that is destined to worship oya to be successfulPeople going to ipo, People going to offaWhenever someone is born with this odù ifáMust worship òrìsà oya and take her as his or her priorityFor him or her to be ...