Home / Àṣà Oòduà (page 121)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Iwosan ogbe inu

Awon nnkan won yii lo maa n se okunfa ogbe inu; ki eniyan maa fi ebi pa ara re nigba gbogbo, jije ounje gbigbona ati iyo pupo ninu ounje ati bee bee lo. Bi a se maa se iwosan naa ...

Read More »

E jowo eyin, abiyamo, e dakun e gba wa ni imoran ..

OOOOOOO Oro naa ti di lbanuje ati edun okan fun molebi mi, e dakun e gba mi ooooo. Mo je Omo odun metadinlogbon (27 years) Taiwo. . . . . . ni Oruko mi, Okunrin ni mi, bakan naa ni ...

Read More »

Awon agbejoro tuntum ti ogbeni saraki sese GBA ni yi o

Ejowo kini oruko won ?

Read More »

Sisi ologe elo ni Suru ooo

Se Eledumare to da IDI yin bi o se mon IDI kaluku yin se ko se da ni in? Awon kan wa sese ma lo ogun abi abere. Se ni tori iranu yi na E wo won oooo. Awon kan ...

Read More »

Awise Awo Agbaye Wande Abimbola

Read More »

Osatura ni kini otito ?

Emi ni ki ni otito ? Orunmila ni otito ni oluwa orun to nto aiye Ogbon ti eledumare nlo Ogbon – nla, opolopo ogbon Osatura ni kini otito ? Emi ni ki ni otito? Orunmila ni otito ni iwa eledumare ...

Read More »

Atorise lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Tina Mba lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Seun Akindele lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Sunny Alli lori eto Gbajumo Osere

Read More »