Arabirin Bamidele Ademola-Olateju lo gbe atejade kan sori ero FACEBOOK re nipa alase Yem-Kem International, Dokita Akintunde Ayeni. O ni gbajue paraku ni maanu naa. Ohun ti arabirin Bamidele tun wa fi kun un ni wi pe, Dokita Akintunde ti ...
Read More »Fayose niso eleja
E tun gbe yewo, Gomina Foyose tun gbe sunmo iya eleja.
Read More »Oba’binrin Asa Solaade Iyaasa: Ohun IFA ati Iwure
ÒÒṢÀ ÒKÈ, ÌBÀ IFA ni ti a ba ji a ki OLU OLU moji mo ki o loni IFA ni to a ba ji a ki Osin, osin moji mo ki o loni ELA ni kan ni somo bibi inu ...
Read More »Omo Gomina Ambode n je igbaladun Sande lowo
Kosi ise lonii ojo Sande l’Alausa. Ile ni Habib Aruna, akowe iroyin fun gomina Akinwunmi Ambode, wa pelu aya re. Awon mejeeji jo n je igbaladun ara won loni miliki.Ki lo tile kan mi na lori oro oko ati iyawo ...
Read More »Awon Foto Kunle Afolayan niluu Kenya
Die ni yii ninu ibudo ere fiimu tuntun Kunle Afolayan, The CEO, ni ilu Nairobi to wa ni Kenya.
Read More »E wo ohun ti won so nipa Basiru Alaaru niluu Abuja
Oju oge orekelewa iyawo K1 oba Fuji tasansan
Titi Masha ni yii, okan ninu awon orekelewa obirin ti K1 de Ultimate fi n segbaladun niyewu. Titi rewa pupo lobirin, oju re ri rekete bi ojo, ibadi aran ti n danilorun nigba gbogbo. [Olayemi, ara n fu mi si ...
Read More »E wo ohun ti Gomina Ambode ko fun awon agbofinro ilu Eko
Gomina Ambode ti ilu eko ti ko opolopo ohun elo bi moto, oko ojuomi, oko ofurufu ati okada fun awon agbofinro ipinle naa lati le gbogun ti iwa idaran ni ipinle naa. Minisita fun eto abenu, Rahman Dambazzau lo soju ...
Read More »Ojulowo-ogidi iya je awon ole ti won mu ni Mowe
Ojo gbobo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo palanba awon igara olosa kan segi laaro ana ni agbegbe Olowotedo Mowe to wa ni masose Eko si Ibadan. Ikanra ni awon eniyan agbegbe naa fi na awon ole taa ...
Read More »