Home / Àṣà Oòduà / AṢẸ: Irosun di awo ẹlẹtà ádífá fun ẹlẹtá eyi..

AṢẸ: Irosun di awo ẹlẹtà ádífá fun ẹlẹtá eyi..

Irosun di awo ẹlẹtà ádífá fun ẹlẹtá eyi tin se owun gbogbo ti ikan ko lori (wọn ni ẹbọ nikose..orùbọ tan lowa di oni re gbogbo)
Njẹ ori ẹni ni awure, eníyan bí ẹbáá ji lowurọ kí ẹdí ẹlẹ́da yin mu ki ẹ wure….ori ẹni láwure…..
Ẹyin eniyan mi ẹ jọwọ ki ẹto jáde ni inu ẹlewá ki ẹ má gbí yan ju lati maba ẹlẹdawa sọ owun gbogbo ti aba nfẹ….nitori pe owun gbogbo lọwọ ori ni o wa…
Mo wá fi asiko yii ṣe ni iwure fun ori kankan wa wipe ni iyoku ki ọdun kopari…ire ayọ wa tin bẹẹ níbẹ kí ẹlẹdawa kogbe kowa…
Ibá nujẹ o kere tábi otobi koni fí ile ẹnikankan wa se ibugbe….AṢẸ

About oodua

4 comments

  1. Ase wa ni tireke! O D’ase!!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...