Home / Àṣà Oòduà (page 149)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Oserebirin onitiata wo ni yii?

#Oniroyin  Olayemioniroyin.com Taani obirin to wa ninu foto yii?

Read More »

Ore idunnu wole fun awon ti Boko Haram pa lekun nipinle Borno

Arabirin yii bi ibeta (omo meta) ni ipago ti won pese fun awon eniyan ti Boko Haram so di alainile lori to wa ni Bama ni ipinle Borno. E wo linki isale yii: @OlayemiOniroyin  

Read More »

Owo awon olopaa te ole ajipata ati komu niluu Ibadan

Ero o gbese ni olu ile ise awon olopaa ipinle Oyo to wa ni Eleyele nigba ti won se afihan awon igara olosa ajipata ati komu gbe fun awon oniroyin niluu Ibadan. Awon ole bi merin yii lagbo wi pe ...

Read More »

Ori iya mi ooooo! Ukwu ore Yemi Alade ti da gobe sile o.

Wahala ti bere si ni sele lori ayelukara bayii, eleyii si bere nikete ti Yemi Alade se afihan foto re pelu awon ore, eni to se apejuwe won gege awon ololufe orin re. Awon eniyan ko tile soro nipa Yemi ...

Read More »

Won we ose awure fomo Poli Ibadan

Eniyan le fi ebi kose owo, sugbon ko rorun lati febi kawe. Wahala igo ni o pa alasuota. Ise akanse, ka ji kawe loru, lo soke lo sode, ka sare wo kilaasi losan pon ganrin-ganrin ni o je komo ile ...

Read More »

#OGULUTU: Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata

E ku asiko yii eyin eniyan mi, ko to di wi pe n maa se alaye ara mi tabi abala Ogulutu to je tuntun to gori Iwe Iroyin Owuro. E je n sare bi yin nipa oun ti won pe ...

Read More »

Kayeefi niluu Eko: omokunrin ti o lese n wa danfo

Kayeefi niluu Eko: omokunrin ti o lese n wa danfo. E le ka ero awon eniyan nipa okunrin yii nibi:

Read More »

Ere Opolo: Matimatiisi to gbona felifeli

Ile itaja kan n ta masiini okada ati keke maruwa. Apapo gbogbo oja ti won ni je. meje (apapo okada ati keke maruwa), gbogbo oja won lapapo si ni taya mokandinlogun. Nje o le so iye okada ati keke maruwa ...

Read More »

Ti o ba je wi pe emi ni Oliseh, ohun ti maa se ni wi pe…”- Adegboye Onigbinde

Vincent Enyeama ti n mu goli fun egbe agbaboolu Super Eagles ti dagbere fun egbe agbaboolu naa wi pe o digba kan na leyin odun metala to ti n sise sin ilu baba re. Igbese ikede ifeyinti pajawiri Enyeama ko ...

Read More »

Diepreye Alamieyeseigha, gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, jade laye leni odun mejilelogota (62)

Diepreye Alamieyeseigha, to je gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, ti jade laye leni odun mejilelogota (62) lana Satide. Iroyin to te Olayemi Oniroyin lowo fi ye wa wi pe aisan ejeruru lo pa gomina naa.

Read More »