Home / Àṣà Oòduà / Ere Opolo: Matimatiisi to gbona felifeli

Ere Opolo: Matimatiisi to gbona felifeli

Ile itaja kan n ta masiini okada ati keke maruwa. Apapo gbogbo oja ti won ni je. meje (apapo okada ati keke maruwa), gbogbo oja won lapapo si ni taya mokandinlogun.

Nje o le so iye okada ati keke maruwa to wa ninu soobu naa, to ba je wi pe taya meji ni okada ni ti keke maruwa si ni meta?

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...