Home / Àṣà Oòduà (page 164)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Ohun tama je lanwa kama pade n’toma jewa. Gbiyan ju lati se Ase !

Ase !!

Read More »

Anu opolopo obinrin si se mi lojo oni !

Hunmmmmmm, Ẹ ku ọsan o, e ku ataaro o, o ga o, anu opolopo obinrin si se mi lojo oni, nitori opolopo ninu won lo ti so aponle ara re nu niti tori eja #300 ati hi malt #100, tabi tori ...

Read More »

Tan fe ku kosi lojo idibo emi pelu obe lajo nlo dibo ,loxxxxxx

E dakun ,oruko wo loda fun mama ?

Read More »

Talo mo oruko, ogbontarigi okunrin ogun yi?

E jo kini oruko, ogbontarigi okunrin ogun yi?

Read More »

Oruko wo ni iwo mo ohun to wa loju aworan yii si?

Read More »

Taani o le se efe (joke) ju ninu awon osere yii ?

Read More »

Egbo eyin eniyan mi Kinni Opin eda laye?

Edakun e ba wa dasi oro to nlo Egbo eyin eniyan mi Kinni Opin eda laye?

Read More »

E ku ojumo eyin omo ile kaaro ojiire. Se daada ni?

Mo gba l’adura wipe bi a tin jade lo fun ise oojo wa, ao ni ko el’esu l’ona. Iko ki n ko ejo l’ese, ayun lo ayun bo l’owo n yun enu. Atepe ni ese n te’na. Ire ila oorun, ...

Read More »

Ogboni – Isese Lagba

Read More »

IWURE ODUN TUNTUN 2015

IWURE ODUN TUNTUN A si ku odun, a ku iyedun. Olodun a wo omo fun wa. Kewekewe koni ko wa l’omo lo. Aseye ni alakan ns’epo ti e Aseye ni tiwa o. Aseti, akoti koni kan wa T’oko, t’aya ati ...

Read More »