Home / Àṣà Oòduà / E ku ojumo eyin omo ile kaaro ojiire. Se daada ni?

E ku ojumo eyin omo ile kaaro ojiire. Se daada ni?

Mo gba l’adura wipe bi a tin jade lo fun ise oojo wa, ao ni ko el’esu l’ona. Iko ki n ko ejo l’ese, ayun lo ayun bo l’owo n yun enu. Atepe ni ese n te’na. Ire ila oorun, iwo oorun, gusu oun ariwa ki eledua gbe ko wa. A pa m’owo owo, ata jere oja.

yoruba

Ewe gbegbe ko gbe ire to wa wa,
ewe ewuro ko je ki oloore wa ko mu ti wa ro.
Ona ki n di mol’oko, ona ki n di mo al’ada, ona ko ma se di mo wa.
Ire l’oju owo nri, ire la o ma ri.

Aseye ni alakan n s’epo, aseye la o se.

Ase

About oodua

One comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Lakurubututu ! “Omo ya jo, omo le yeni”

Omolade,Omolowo,Omolola,Omo ni ola,Omoni’yi Omo’leye, Omolabake, Omolabage, Omopariola Omojowolo, Omosunbo, Omofowokade, Omofowokola Omotoriola, Omorinsola, Omorinsoye, Omobobola, Omoyosola Omoboboye, Omoyosade,Omoyosoye, Omodapomola, Omodapomoye Omoboriola, Omoboriola,Omotanshe,Omotanoshi, omo ju oun gbogbo lo, Aakun dabo ore wa toju omo re nitori awon ni Ojo ola re, gbogbo Eni ti o ti bi ko ni yan ku Agan ti ko ti bi,yio fi owo Osun pa omo lara, a ti se odun ajodun awon ewe ti odun yii, K’edumare je ki a tun se opolopo re lori ...