Home / Àṣà Oòduà (page 28)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

O lápátí

Kò tirẹ̀ lápátíKò sí ẹni lè gbà pe kí wọ́n dojú ìbọn kọ òwun Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun ti a wọ inú rẹ̀ yí wípé ògún lákayé kò ní dojú ìjà kọ èmi àti ẹ̀yin tọmọ tọmọ ...

Read More »

E ku Ose Ifa

Aráká-AjagaAràkà-AjagaAdifun Eniyan Ti Mú Iyè Meji Sin ÈdúÈnìyàn Ti O Sin Èdú,Ko Ma Se Iyè MejiAráká-Oku-AjagaAràkà-Oku-Ajaga ??Ase Tedumare?? ?Ifabukky Care?

Read More »

Ìgbín

Àkòrò ní ìgbín fà gungi Ìgbín kò lọ́wọ́ Ìgbín kò lẹ́ṣẹ̀ Àkòrò ní ìgbín fà gungi Mo sé ní ìwúre fún èmi àti ẹ̀yin ní ojúmọ́ tòní wípé Olódùmarè yoo tì wá lẹ́yìn, ìgbìnyànjú wa láti gun òkè ọlà, kò ní já sófo

Read More »

ERÍWO YÀ! ERÍWO YÀ!! ERÍWO YÀ!!!

Gbogbo ẹ̀yin Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀; Ojú rẹ rèé o : Babaláwo Babájídé Ọ̀ṣúnníyì (Olúwo Jọ̀gbọ̀dọ́ Ọ̀rúnmìlà). Ní òní yìí ni ìgbẹ́jọ́ ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ṣẹ̀ṣẹ̀ padà sí ìdí Ifá / Ìṣẹ̀ṣe (lẹ́yìn ikú Baba rẹ ní ...

Read More »

OAU se ìràntí àwon akoni tí won pàdánù èmí won sí owó àwon omo egbé òkúnkùn ní ogún odún séyìn.

OAU se ìràntí àwon akoni tí won pàdánù èmí won sí owó àwon omo egbé òkúnkùn ní ogún odún séyìn. Àwon alámòójútó àti akékòó ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo University ti ilé- ife, máa péjo sí gbàgede Amphitheater tí ilé èkó ...

Read More »

Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..

Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOrí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOlú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díNítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ Mo sé ní iwure fún ...

Read More »

Èèmò lukutu pébé.

Òdókùnrín tí ó n fi èro ayélujára gbáni, tí ó n se Yahoo yahoo, ni owó ti tè níbi tí ó ti n gbé òkú arábìnrin tí ó pa sí hòtélì lo. Owó sìkún àwon agbófinró ti te odókùnrin tí ...

Read More »

Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà.

Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà. Omo egbé agbá bóòlù fún orílè èdè Nìjíríà tí na àwon omo egbé agbá bóòlú Cameroon ní méta ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó.

Arewà obìnrin kan ni ó gbé o n je omo (oyàn) rè han nínú àwòrán òun àti oko àfésónà kí won tó se ìgbéyàwó. Arábìnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà ní ó fi orí oyàn hàn níbi àwòrán ...

Read More »

Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.

Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won. Àwon arewà omodé méjì yí, ni won ti kí a mo rírì ìfé tí èjè máa ni sí ara won. Omokùnrin kan láti orílè ...

Read More »