Kemi Olunloyo so báyìí wípé! Àwòkóse burúkú gbáà ni Linda Ikeji àtiwípé òun ni àwòkóse rere.OK olunloyo so òpòlopò àsírí nípa oyún inú Linda Ikeji àti nípa ara rè pàápàá. Àtiwípé Linda Ikeji ti kó bá òpòlopò òdóbínrin.
Read More »Sùúrù lógbà.
Ìsé kìí se ohun àmúseré Ìyà kìí se ohun àmúsàwàdà Ebi ń pamí kìí mérìń p’ani Sebí ebi kìí w’onú Kí òrò míràn wòó Ojú tí ń kúkú pón isin Kìí se àpón ku Bí kòse àpónlà Bówù kópé títí ...
Read More »A o ni ri ogun aisan
A o ni r’ogun aisan! Ifa ni: Pere ni tewe iyeye, aloye ni ti peregun; Piri l’eye olongo n ji; A kii b’okunrun eye lori ite; Gege lowu alantakun n fuye; Ota kii ku, ota kii run; Koko lara ota ...
Read More »Iwure Ori
Orí mi, gbe mi o! (My Orí, support me) Ori lo da mi (Ori is my Creator) Eniyan ko o (It is not man) Olodumare ni (It is Olodumare) Ori lo da mi (Ori is my Creator) Ori Onise (Ori, ...
Read More »Ifa naa ki bayi wipe: Emi ote, Iwo ote
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku ose ifá toni, emin wa yio se pupo re laye ase. Gegebi a se mo wípé oni ni ose ifá, e jeki a fi odù ifá mimo ...
Read More »Aalo apamo Toni: Itan aja ati ijapa!
Alo ooooooo, alo oooooooo. Itan aja ati ijapa. Ni ojo kan iyan mu ni ilu kan, ko si onuje, baba agbe kan wa, to je ipe ohun ni kan ni o gbin n kan si oko re. Ti awon ara ...
Read More »Yoruba Esu & European Satan: What a generational Colloquial misconceptions !
Satan is an European language and it’s best interpreted by the same European people. Conceptually, in Yoruba culture, ESU and Satan remains different in meaning and does not mean the same. While Satan relates to wickedness of people, Yoruba ESU ...
Read More »Àfi kí á ma dúpé.
Àfi kí á ma dúpé . Ìwo tí o wà láyé Tí ò ń jeun àsìkò Tí o tún ń wo aso àsìkò Ó tó kí olúwa rè sopé Olúwa tún wá ba o se é Ó tún fún o ...
Read More »ORIKI ILORIN Ilorin afonja.
ORIKI ILORIN Ilorin afonja enudunjuyo Ilu to jinna s’ina To sunmon alujana bi aresepa Ilu tobi to yen,won o leegun rara Esin l’egungun ile baba won Akewugberu ni won A s’adura gbore Aji fi kalamu da won lekun arise kondu ...
Read More »ORÍKÌ OFA
Otunba Ikanni: Iyeru okin olofa mojo, Omo olalomi, omo a basu Jo o ko Omo la a re, bu u re, Okan o gbodo jukan, Bokan bajukan Nile olofa mojo, Ogun Oba ni i kowon ni roro, IJA kan IJA ...
Read More »