Gbajúgbajà amòfin oloyè Mike Ozekhome, SAN se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé ogóta odún ni ilé-ìtura Sharaton tí ó wà ní ìlú Abuja nínú àwon tó lo ni Ààre télè Goodluck Jonathan, ìyàwó rè Patience, igbákejì Ààre ...
Read More »Ewo nkan tí àwon èèyàn se fún àwon olè meta tí won jí kòkò obè.
Gégé bí ò n lò èro ayélujára( Facebook) tí ó pin àwòrán àwon òdókùnrin méta yí tí a gbó wípé won sì wà ní ilé-èkó girama ni won fi ìyà je won tí won sì so won kó sí ojú ...
Read More »Awakò okò epo NNPC pa arákùnrin kan ní Aba.
Gégé bí Sopu tí ó n gbé ní Aba se so, olóògbé tí àwòrán rè hàn n’ísàlé yí ní awakò okò epo ti NNPC pa. Òpòlopò ènìyàn sì péjo láti ya àwòrán rè láti jé kí àwon mòlébí ...
Read More »Tracy àti Treasure Daniel se ayeye ojó ìbí won pèlú àwòrán tí ó ya ni lénu.
Àwon òsèré tí ewà won ya ni lénu tí ó sì pa ni kú ni àwon ìbejì yí . Treasure àti Tracy Daniel tún lé odún kan si . Àwon ìbejì yí ti hàn ní àìmoye eré orí ...
Read More »Àwòrán tí ó wuyì tí D’banj àti Wande coal yà tí won sì wo ara won in àwò dé eyinjú.
Ó ti pé tí a ti rí àwòrán Wande coal. Sùgbón èyí fi hàn wípé òré sì ni àwon méjèèjì…
Read More »Òdómobìnrin tí ó gba òrékùnrin tè s’ílé nítorí wípé kò ní isé l’ówó bá pátá àti róbà ìdábòbò nínú ilé rè.
Gégé bí ìtàn se so è yun-ùn tí won pín sí orí èro ayélujára (IG) ti Joro Olumofin. Òdómobìnrin tí ó gba òrékùnrin rè tí kò n’ísé l’ówó gbé nínú ilé rè ní Eko padà délé láti ìrìn-àjò ...
Read More »Àwòrán Afárá(Bridge)tí ó já tí won sì ti kò sílè ní ìlú Ilorin .
Afárá (Bridge ) yí ni òjò ti gbá dànù láti bí osù díè séyìn látàrí òjò nlá tí ó rò tí àwon ìjoba kò sì se nkankan si . ònà alágbàdo ni afárá yí wà . Nígbà ...
Read More »Àwòrán ìsìnkú Tagbo Umueke ní ìpínlè Anambra .
Òré Davido, tí ó n jé Tagbo Ifeatuchukwu Umueike ni ó sùn re ní ogún’jó osù kèwá odún, 2017 (20/10/2017) ní ìlú tí a bi sí. Ní ìjoba ìbílè Osumenyi ní ìpínlè Anambra . Àwon òré ...
Read More »Òdómobìnrin odún mókàndínlógún pín àwòràn ilé tí ó rewà tí sugar daddy rè rà fun .
Òdómobìnrin odún mókàndínlógún tí ó tún jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) ti gba àwon òdóbìnrin ní ìmòràn wípé kí won múra sísé kí won sì gbàgbó nípa èróngbà olórun sí won nígbà tí ó n ...
Read More »Òdómokùnrin kan ní orílè-èdè Ghana ni ó pa ara rè látàrí wípé àwon ebí rè kò gbà kí ó fé ìyá omo rè .
Òdómokùrin kan ni orílè-èdè Ghana ni ó pa ara rè léyìn ojó díè tí ó pín nípa àwon ebí rè tí kò gbà fun kí ó fé ìyá omo rè….
Read More »