Home / Iroyin Pajawiri (page 114)

Iroyin Pajawiri

Ijamba oko niluu Eko lojo odun keresimesi

Ti e ba muti, e ma wako; ti e ba wako, e ma muti. Okunrin kan lo koja lo sorun lojo odun keresimesi to koja yii ni akoko ti gbogbo eniyan n yo ayo iwasaye Jesu olugbala araye. Ijamba oko ...

Read More »

Owo ti te Jaguda, Mohammed Isah to lu komisanna olopaa meji ni jibiti

Sebi ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo awon olopaa ilu Eko ti te omo gambari onijibiti kan ti oruko re n je Mohammed Isah, to lu komisanna ipinle Ondo ati Anambra ni jibiti. Omokunrin onijibiti naa ...

Read More »

Ikini odun lati owo Olayemi Olatilewa Oniroyin Agbaye

Olayemi, odun to n bo yii, odun emi ati iwo ni. Eyin e fota sile ki won ma gbogun. E fika eniyan sile ki won ma soogun. Mo tile tun gbo wi pe awon kan tun lo n bogun onire. ...

Read More »

Yinka Ayefele sodun fun awon alaini ati omowewe

Aimoye awon omo wewe ni won pejo si bi ayeye odun keresimesi ati babakeresi ti ile ise redio Fesh FM ti Yinka Ayefele eleyii to waye ni Music House, ile orin Ayefele, to kale siluu Ibadan. Asekagba naa lo waye ...

Read More »

“Oju Mimiko ni PDP yoo fi poora nipinle Ondo” – Oloye egbe APC

Okan pataki ninu awon oloye egbe APC nipinle Ondo, Niran Sule-Akinsuyi, ti so yanya wi pe niseju Gomina Olusegun Mimiko ni egbe oselu PDP ipinle naa yoo fi di ohun a-fi-seyin teegun fiso. Oro yii lo n so nigba to ...

Read More »

Faleke n mura ija nipinle Kogi *Omo oloogbe Abubakar Audu n be leyin re.

*Omo oloogbe Abubakar Audu n be leyin re. *Kilode ti Tinubu ko da soro naa? Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Lojo Aje to koja yii ni rugudu ti n lo lagbo oselu nipinle Kogi tun bureke si i nigba ti Ogbeni ...

Read More »

Esun idigunjale la o fi kan eni to ba gbegidina ti n gbowo odun” Olopaa Ipinle Ogun

Komisanna awon olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Abdulmajid Ali ti kede wi pe,ile ise olopaa ipinle Ogun ti wa ni imurasile lati gbogun ti iwa idaran to seese ko suyo lasiko poposinsin odun taa wa yii. Ninu oro Ogbeni Abdulmajid, eleyii ...

Read More »

Se oro Buhari ko ta leti awon asofin ni?

Okan ninu awon asofin, Honourable Essien Ekpenyong Ayi (PDP) lati ipinle Cross River n sun ni akoko ti Aare Buhari n ka iwe eto isuna odun 2016 niwaju ile igbimo asofin Abuja.

Read More »

E wo ohun ti oyinbo amunisin se lodun 1908

Awon oyinbo amunisin lati ilu Belgium yegi fun omokunrin, omo odun meje (7) niluu Congo lodun 1908. Ogbeni Femi Fani-Kayode lo se afihan foto yii lori ayelujara. Okunrin naa si tun fi kun un wi pe, ninu awon oyinbo amunisin to ...

Read More »

Divination Process: Ifa Verses (Odu Ifa) 16 Principal Odu

Ifá is a system of divination that originated in West Africa among the Yoruba ethnic groups. It is also practiced among believers in Lucumi, (sometimes referred to as Santería), Candomblé, West African & Diaspora, and similarly transplanted Orisa’Ifa lineages in ...

Read More »