Ní’sàlé ni àwòrán ìsìnkú olóyè nínú ológun (Corporal) Odudu Davis tí ìbon pa nígbà tí osù kàrún di ogbòn ní inú odún yìí (30/5/2017)láti owó àwon olóòpá ojú omi (naval officer) nígbà tí àwon olóòpá àti àwon olóòpá ojú ...
Read More »A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo.
A kú àyájó odún *Òmìnira* ti *orílè Èdè Nàìjíríà* ?? lónìí ooo. Èmí wa yóò se púpò rè láyé. E jòwó, e má sì gbàgbé láti se *ìwúre* fún orílè èdè *Nàìjíríà* ?? nítorí wí pé *”Ìròrùn igi ni ìròrùn ...
Read More »Oga Bello àti iyalode Binta Mogaji
Awon agba osere apanilerin meji
Read More »Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, Olorun eledumare yio jeki aje fi ile wa se ibugbe loni o ase. Odu ifa IROSUN OSE/ALAJE lo gate laaro yi, ifa yi fore aje lopolopo fun akapo ti o ...
Read More »Musa Musa, olóòpá tí ó fó ilé Jonathan.
Àwon Agbófinró ti rí àwòrán olóòpá kan tí ó jé atónà fún àwon ìgárá olóshà tí ó fó ilé Ààre télè Goodluck Jonathan ní Gwarimpa Abuja. Musa tí a gbé lo sí ilé-ejó gíga díè (magistrate) ní ojó ìségun tí ...
Read More »Omokùnrin kan tí orúko rè ńjé Charlyboy subú lulè nígbà tí won ń se àtakò Buhari.
Àmóhùnmáwòrán Channels ti pín fídíò tí ó se àfihàn omokùnrin kan tí ó ń jé Charlyboy nígbà tí ó subú lulè nígbà tí won ń tako Buhari lówó ní ìlú Abuja láàárò òní. Àwon Agbófinró fín tajútajú àti omi láti tú ...
Read More »Òrékùnrin mi ń bínú sími.
E jòwó, mo fé àmòràn lórí ohun tí ó ye kí n se, osù kewàá rèé tí mo ti mo Òrékùnrin mi, a sì ní ìfé ara wa, sùgbón Òrébìnrin rè télè sì ń dàá láàmú, èyí sì ń jé ...
Read More »Eré odún Òrìshà ní orílè èdè UK Edinburgh Fringe.
Àwon Òrìshà, Yemoja, Oya, Òshun, Elégba àti òshóòsì jé àwon Òrìshà tí ó dúró fún èdá ènìyàn ní gbogbo ònà, tí won sì máa ń wá sí ayé gbangba. Nígbà tí akoni wa òshóòsì, tí ó jé ògbójú ode, tí ...
Read More »Olùkó kan ní Benue ni won ní kí ó San mílíònù kan àti ààbò Náírà (₦1.5m) fún owó orí.
Arákùnrin tí ó sèsè parí èkó, tí ó sì ń sisé olùkó ní ilé-ìwé aládàáni girama kan tí ó fé fé ìyàwó ní àwùjo kan ní Zone “A” ní ilè Tiv ní ìpínlè Benue, ni won ti fún ní àwon ...
Read More »Àwon ènìyàn Nàìjíríà ní orí èro ayára-bí-àsá so pé kí won fún Cynthia Chinecherem ní egbèrún lónà lónà aárùndínlógbòn lé ní èédégbèta náírà
Àwon ènìyàn Nàìjíríà ní orí èro ayára-bí-àsá so pé kí won fún Cynthia Chinecherem ní egbèrún lónà lónà aárùndínlógbòn lé ní èédégbèta náírà (#525k) fún níní àmì “A” mésàn-án (9A1) nínú èsì ìdánwò àsekágbá girama. Rántí Cynthia Chinecherem, Arábìnrin tí ...
Read More »
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
