Home / Iroyin Pajawiri (page 77)

Iroyin Pajawiri

Àwòrán Obanikoro àti Oluremi Tinubu àti àwon omo egbé APC tó kùn ní ìlú èkó.

Ní ìsàlè yìí ni àwòrán sineto Obanikoro àti sineto Oluremi Tinubu àti àwon tó kùn. Ní ìpàdé kejilélógún (22nd) ní ibi ìpàdé àwon sinetò ní agbègbè èkó …. English Version after the page break

Read More »

Inú àwon olólùfé 2baba dùn púpò nígbà tí won rí olólùfé won ní Glomega music tour tí ó wáyé ní Victoria Island, ní ìlú èkó. 

Gbajúgbajà olórin 2baba jé òkan lára àwon tí ó korin ní Glomega tour ní  VI ní ìlú èkó. Ó tún wú àwon ònwòran lórí nígbà tí ó f’akoyo lórí ìtàgé.  Ewo àwòrán bí ó se Ń dá won lárayá n’ísàlè.. ...

Read More »

Àwon olólùfé Biodun Okeowo wí fun pé kí ó pa àwòrán rè tí ó wo aso tí ó fun ré. 

Òsèré Biodun Okeowo tí a mò sí Omobutty, ni àwon olólùfé rè ń sòrò sí látàrí àwòrán tí ó pín ní bi tí ó ti wo aso tí ó gbé èyà ara rè jáde… Continue after the page break for ...

Read More »

Akékòó Odún Keta (300l) Ti Oau Ti Eka Èkó ‘Pharmacy’ Rì Sómi, Tí Ó Sì Kú Sí Odò-ìwè (Swimming Pool) Ní Hòtéèlì. 

Akékòó odún keta (300l) ti eka èkó pharmacy, Obafemi Awolowo University; pàdánù èmí rè Lánàá léyìn ìgbà tí ó rì sómi nínú odò-ìwè (swimming pool) ní hòtéèlì tí a mò sí Hilton. A mò ó sí Fatile Emmanuel. Ìsèlè yí ...

Read More »

Owó Sìkún Àwon Olóòpá Te Arákùnrin Tí Ó Máa Ń Jí Okò Gbé Ní Yenegoa. 

Nígbà tí won ti mu fún èsùn kan náà. Arákùnrin tí ó wà nínú àwòrán ní ìsàlè yìí tí ó yan isé okò jíjígbé láàyò ni owó sìkún àwon olóòpá bà ní Yenegoa, ní ìjoba ìpínlè Bayelsa fún ìgbà keta. ...

Read More »

Oko Mi Máa Ń Fowósí Fóòmú Rè Wípé Òun Kò Tí Ní Ìyàwó ,erànmílówó.

 E jò ó Erànmílówó. Oko tí ó fémi sílé láti odún mérin séyìn, máa ń fowósí fóòmú rè wípé òun kò tí ní ìyàwó nígbà kúgbà tí ó bá ye kí ó so pé òhun ti láya. Yàtò sí ìyen ...

Read More »

Ìdí Tí Ó Fà Á Tí Mi Ò Ní Fi Lo Káàdì Ìrántí (Memory Card) Láyémi Mó. 

Ìdí méji pàtàkì tí mi ò fi lo káàdì ìrántí (SD card) mó. SD card tí a mò sí káàdì ìrántí (memory card) tí a tún mò sí káàdì ìrántí ìtá “external memory “,ní tòótó ó jé ohun tí ó ...

Read More »

Ní Iwájú Si : Nípa Ìlànà Oba Ifá Ti Gúúsù America (South America).

Àrídájú ti so wípé… 1. Àwon ènìyàn kan wà tí won ń lo orúko àti ipò Aláàfin láti fi lu àwon tí kò mò nípa Àsà yorùba ní jìbìtì ní ìlú òyìnbó. 2. Àwon babaláwo tí ó wà lábé ilé-ifá ...

Read More »

Fatai Owoseni sàkóso lílo bíbò ní Ikorodu láti owó omo oòduà rere !

Kàyééfi ńlá gbáà ni súnkere fàkere okò tí ó selè ní ìròlé àná ní bóòsì dúró Agric (Agric bus stop), Ikorodu ní ìlú Èkó. Tí ó kan ògá pátápátá ilé-isé olóòpá (commissioner of police) Ògbéni Fatai Owoseni láti yo òpòlopò ...

Read More »

Àwòrán Kí Ó Tó Di Ojó Ìgbeyàwó Láàrin Eléyàmeyà

Omo Ooduarere tún gbé tuntun dé ooo, àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó láàrin eléyàmeyà. Femi (yorùba) àti Mma rè tí ó ń jé OGECHI láti (River), inú won dùn púpò gan bí won se ya àwòrán papò nínu aso ...

Read More »