Home / Ẹkọ (page 2)

Ẹkọ

What is Ifá’s position on GAY marriage?

My RESPONSE to the very much insistently asked questions from friends and associates, within and mostly outside Indigenous Faith of Africans believers ( IFA ), on Ifá’s position about the global ranting GAY marriage that has arouse much confrontations between ...

Read More »

Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba

Mooko-mooka: Akoto ede Yoruba Ni abala mooko-mooka ose yii, akoto ede Yoruba ni a maa gbe yewo. Akoto je ona ti n gba ko ede Yoruba sile laye ode-oni. Eleyii to yato si ti aye atijo.   Aye Atijo Aye ...

Read More »

Onka ede Yoruba 100 – 20,000

Orisun  Onka ede Yoruba 100-Ọgọrun 110- Adọfa, àádọ́fà 120- Ọgọfa 130- Aadoje 140- Ogoje 150- Adọjọ, àádọ́jọ 160-Ọgọjọ 170-Adọsan, àádọ́sán 180- Ọgọsan 190-Mẹwadinigba 200-Igba E tesiwaju ni isale lẹhin iwe Bireki yii (Continue after the page break bellow)

Read More »

Ifa physiology: Ojú/Eyes

Ojú. Ojú lalákàn fi í sọ́rí. Ojú oró ní í lékè omi. Ojú ò ní tì wá lótù Ifẹ yìí láíláí. Ojú ò níí relé de ìkankan nínú àwa ọmọ Awo. Eyes–Oju With the eyes, the crab watches the ori. ...

Read More »

IFA ANATOMY: Etí/ Ear

Etí. Ear, also fringe, edge, border, perimeter. Ó pawo lékèé Ó pÈṣù lólè Ó wá kọtí ọ̀gbọin sẹ́bọ Etí odò yato sétí aṣọ. Ọ̀rọ̀ tí a bá fẹ́ kí aditi gbọ́ Etí ọmọ rẹ̀ là á ti í sọ o. ...

Read More »

E je kawa imo ku imo Ewo lo to na ninu awon oro won yi

1) Ki lori lobe to fi wa iru so wo  2) ki lori lobe to fi waru owo  3) ki lori to fi garu owo  4) ki lori lobe to fi wa owo ru 5) ki lori lobe to fi ...

Read More »

Kinni eyin npe ladugbo yin

Wonwo re lede wa legbado kinni eyin npe ladugbo yin ,obe re ninu ata dindin

Read More »