Agba ninu ise amofin to tun je agbejoro ti n ja fun eto omoniyan, Ogbeni Femi Falana ti seleri lati gbe oludamoran nipa eto abo fun ijoba apapo tele ri, Sambo Dasuki ati awon akegbe re ti won ka modi ...
Read More »Taye Ogunlaja: Won ti pa oloye omo egbe NURTW tiluu Eko
*Won gun un lobe lorun pa ni Awon olopaa olotelemuye, eka ti ile ise olopaa ti n risi iwa idaran to wa ni Panti, Yaba ti bere ise iwadii to gbepon bayii lati mo odaju eda to seku pa Taye ...
Read More »Ile ejo to gaju lo ni yoo pari idaju iku Reverend King
Ile ejo to gaju nile yii ti kede ojo kerindinlogbon osu keji odun ti n bo (26/02/15) gege bi ojo ti igbejo adari ijo Christian Praying Assembly, Reverend Chukwuemeka Ezeugo, ti gbogbo eniyan mo si Reverend King yoo ma waye. ...
Read More »IROYIN OWURO ose yii ti jade oooooooo
Ese ‘o gbero ni Ikenne Paradise ni mama wa bayi – Pst Adeboye Opelope Mama Kapenta nii nba je – Pst Bakare Okunrin to feran ibalopo pelu okunrin farahan ni Abeokuta Oju to maa ti awon ti won nbu ijoba ...
Read More »E wo ohun ti Gomina Ambode ko fun awon agbofinro ilu Eko
Gomina Ambode ti ilu eko ti ko opolopo ohun elo bi moto, oko ojuomi, oko ofurufu ati okada fun awon agbofinro ipinle naa lati le gbogun ti iwa idaran ni ipinle naa. Minisita fun eto abenu, Rahman Dambazzau lo soju ...
Read More »Ojulowo-ogidi iya je awon ole ti won mu ni Mowe
Ojo gbobo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo palanba awon igara olosa kan segi laaro ana ni agbegbe Olowotedo Mowe to wa ni masose Eko si Ibadan. Ikanra ni awon eniyan agbegbe naa fi na awon ole taa ...
Read More »Eto idibo gomina ipinle Kogi di fopomoyo
*Faleke n binu, ara ilu n sofo *Iwe ofin ruju mo awon amofin loju *Won tun ni kan fomo Audu je gomina apapandodo Leyin iku Abubakar Audu, oludije fun ipo gomina labe egbe oselu APC nipinle Kogi, eni to jade ...
Read More »Kini ijoba n se nipa awon ti n se ayederu?
Orisun iwe Iroyin Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon iroyin bayii, a kan maa n gbo ...
Read More »O di gbere! Abubarka Audu wole sun
O ku die ko je gomina niku mu lo. Igba ti okiki re bere si ni i kan, lo wole sun. Ojo ti idile re i ba fo fayo, ni won bo sinu ibanuje nla. Ile aye asan, ile aye ...
Read More »Awon akekoo LASU yari, won ni awon alase n ko leta si yanponyanrin
Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon omo egbe akekoo Ifafiti tilu Eko, Lagos State University Students Union (LASUSU) ti bere si ni fariga pelu ifehonuhan latari bi awon alase ileewe naa se fi owo kun owo igbaniwole awon akekoo tuntun. Ifehonuhan ...
Read More »