Home / Awọn Iroyin Agbegbe (page 2)

Awọn Iroyin Agbegbe

Àrùn burúkú fé̩ tú Queens college

Arun iba buruku kan n da yanpon- yanrin sile bayii ni ile-ise awon obinrin (Queens college) to wa ni ilu Eko.Ironu ti dori awon agba kodo ni ipinle Eko bayii paapaa julo fun gbogbo awon to lomo nibe. Ile-iwe yii ...

Read More »

Fayose kò mo̩ bò̩ò̩lì àti àgbàdo je̩ tó mi,àmó̩… – Fayemi

Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re.Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to wa laarin oun ati gomina ...

Read More »

Omo Egbe Yoruba ati ‘OPC’ (Oodu Peoples Congress) Fajuro lori rogbodiyan ti o sele ninu ile ife

Awon omo egbe apapo-Yorùbá-titi eka –oselu, Afenifere ati awọn omo egeb (Oodua Peoples Congress), OPC, ti fariga nipa rogbodiyan ti oun lo ni ilu Ile Ife. Ninu oro kan ti abenugo fun eggbe Afenifere kán so eyi ti un se ...

Read More »

Jegudujera: EFCC tun ti gbe ebi Alison-Madueke niluu Abuja

Awon Yooba bo, won ni tina ko ba tan laso, eje ki i tan leekanna. Awon ajo ti n gbogun ti iwa jegudujera ati sise owo ilu mokunmokun, EFCC, ti gbe arakunrin Donald Chidi Amamgbo to je okan lara ebi ...

Read More »

“Efon ti n fa kokoro Zika wa ni Naijiria, kosi ti gboogun”- Minisita Ilera

Minisita fun eto ilera, Ojogbon Isaac Adewole, ti se idaniloju alaye wi pe, efon abami ti n sokunfa kokoro Zika ti ko gboogun ti wa ni Naijiria. Bakan naa lo si ro awon eniyan lati se ohun gbogbo ni ikapa ...

Read More »

Ambode ti yan oga agba tuntun fun ileewe LASU

Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode ti yan Ojogbon Olanrewaju Fagbohun gege bi oga agba tuntun fun ileewe Ifafiti ti ipinle Eko, LASU. Ikede yii lo waye ninu atejade ti komisanna fun eto iroyin ati agbekale ilana, Ogbeni Steve Ayorinde ...

Read More »

Awon tisa ipinle Kwara taku sori idasesile ti n lo lowo

http://www.olayemioniroyin.com/ Idasesile awon oluko alakobere to ti bere lati ojo Aje to koja yii nipinle Kwara ni awon egbe oluko ti temu mo o wi pe yoo si ma tesiwaju ayafi ti ijoba ba san gbese owo osu meta ti ...

Read More »

Yunifasiti ijo Mountain of Fire yoo bere eko kiko lojo Monde

Gbogbo eto ti to bayii fun ileewe giga ti ijo Mountain of Fire and Miracles Ministries (MFM) eleyii ti won pe ni Mountain Top University lati bere eko kiko fun awon akekoo lojo Monde ose yii, 21/12/15. Eto ibere eko ...

Read More »

Nipinle Ondo, awon osise ko rowo osu gba lati sodun Keresimeis

*Ijoba da awon osise 62 duro lenu ise Orisun: Olayemioniroyin.com Nibayii, Trade Union Congress (TUC) eka ti ipinle Ondo ti n ro gomina ipinle naa, Olusegun Mimiko, lati san awon owo osise ti won je seyin ati awon ajemonu won ...

Read More »

Nipinle Ondo, eniyan meji koja sorun nibi ija NURTW

O kere tan awon eniyan bi meji ni won gborun lo ni Ikare-Akoko to wa ni ipinle Ondo nigba ti awon eniyan bi mewaa farapa koja bikiafu nibi ija to wayii laaarin awon omo onimoto.   Wahala to bere lati ...

Read More »