Arira mase fi ina re na mi o! Aase! A ku Ose Sango! Cc- IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »Demo Blog With Map
Abi e roju aye bi?
Orewa nso fun ara ile wipe ki won Ba oun gbe orin, sugbon won o da loun, lo ba binu lo Si oko o da orin sugbon won o fun lounje, o tun lo si Odo o da orin won ...
Read More »Ounje emi fun t’ooro yii ( 20 – 07 – 2016 )
HUN !!! # Odo to gbagbe # Orisun … Gbigbe nii gbe … WOO ORE WA !!! Ibi Ipile eda L’orisun won.. Ibi Eniyan ti lalehu ni Ipile re… Eni to bini Orisun eni nii se… Eniyan to wo’ni dagba ...
Read More »Iyawo: mi o le gba ki iya oko mi gbe pelu mi lailai.
Olotu:kini ikan tori tofi ni o le gba ki iya gbe pelu re,gbogbo awon eyan loti ba e so,o ko,o loni gbo,won tun gbe e wa sori afefe,agidi yi nan lotun lo.Kini ikan to sele gan. Iyawo:seri olotu,mole gba ki ...
Read More »Ewesooo Dede Ewen Goons Mi
Proudly IJEBU
Read More »Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alfa Ola Akeem Totofun’un ti won je okan pataki ninu ebi Ooduarere. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu ...
Read More »Ojumo Ire
B’ojumo ba mo .. Ooye a la #peregede.. A D’ifa fun Peregede tii se yeye #Ojumo . A KU OJUMO #Ojumo to mowa Lonii. #Ojumo_Ire gbogbo ni yoo je funwa lase Oba mi Oke .
Read More »Elesin Oyan
Iba Orunmila Bara Agbonniregun; Elesin Oyan; Adagbaa Ojomu; Gbolajoko Omo Ere l’apa; Baba Okinkin ti n m’eyin erin fo; Odudu tii du ori emere ti o je ko fo; Atori eni ti ko sunwon se! Iba Baba o!
Read More »Oniwowo ado! Baba dakun ma na mi o! Aase!
OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa
Read More »Foto ode’oni – 13.07.2016
Saheed osupa akorede ati baba wande.
Read More »