Edaku, e fun foto yi ni Oruka kan ?
Read More »Demo Blog With Map
Oro Sunku: Ore Mi, Iran Kerin
(Ni nnkan bi aago meje irole ni ibugbe awon obinrin ni ogba Yunifasiti, ero po nibe lokunrin lobinrin. Awon kan n wole, awon kan n jade. Awon okunrin miiran wa ninu oko ayokele pelu awon omoge, won n soro. Awon ...
Read More »Omidan asewo ti se ‘kerewa’ koja sorun alakeji
Awon Yooba bo, won ni owo tada mo ni kada lehin. Iku ogun ni i pa akikanju, omi ni pada wa pa omuwe lodo. Okan ninu awon omo asewo ilu Abuja ti oruko re n je Omidan Ome Enyi lo ...
Read More »Femi Adebayo, Funke Akindele, Mercy Aigbe, Toyin Aimakhu nibi ami eye Africa Magiki 2016
Aimoye osere lo peju sibi ami eye (Africa Magic Viewers Choice Awards) 2016 to waye niluu Eko. Eyi to waye yii ni i se elekerin iru e. Oruko awon olubori ami eye naa wa nisale .
Read More »Won ti pago lori maanu to fowo kan oyan omoge
Arabirin, Ifeoma Okoroafor, eni odun mejidinlogbon (28), lo ti salaye fun ilejo Upper Area Court to wa niluu Abuja wi pe, Ogbeni Musa Goddy fowo gbe oun loyan jo ni oun se fo nigo lori. Ogbeni Musa lo fejosun lago ...
Read More »Owo Jegudujera Abacha: Ile ejo ti fesun kan Obasanjo ati Jonathan
*Won tun ranse si Yar’Adua lode orun wi pe ko wa salaye *Ile ejo ti gbe ise to le fun Aare Buhari lati se Obasanjo, Yar’dua ati Jonathan Kootu ijoba apapo to gaju lo to kale siluu Eko, Federal High ...
Read More »“Awon soja yin mi ni bajinatu, won fe pami” – Olu Falae
*Awon ika eniyan wo lo wa nidi isele yii? *Se agbanipa ni won tabi awon soja ti won se palapala nigboro? Oloye Olu Falae ni ori ti koyo bayii lowo iku ojiji nigba ti awon soja kan ti enikeni ko ...
Read More »Iyanu ti sele nipa awon omo Babington Ikorodu ti won jigbe
Ni ojo Aje to koja yii (29/02/15) ni awon ajinigbe kan yawo ileewe Babington Macaulay Junior Seminary School to kale si agbegbe Ikorodu nipinle Eko ti won si ji awon omo obirin akekoo meta salo raurau. Gege bi alaye ti ...
Read More »Awon ojogbon fi oye dokita da Tinubu lola
Oloye agba egbe APC, Asiwaju Ahamed Bola Tinubu ni won ti foye dokita dalola bayii ni ogba Yunifasiti tiluu Abuja. Idalola agba oloselu to je gomina ti yoo je sikejila (12th) nipinle Eko lo waye ninu ayeye ikojade awon akekoo ...
Read More »Rogbodiyan Mile 12: “Won ja omo ikoko gba lowo mi” – Abiyamo
Leyin rogbodiyan to be sile ni agbegbe Mile 12 to wa niluu Eko l’Ojobo ose to koja yii (03/03/16), okunrin kan ti oruko re n je Daniel Igba lo ti ke gbajari sita wi pe, awon kan ja omo gba ...
Read More »