Home / Demo Blog With Mappage 145

Demo Blog With Map

E wa wo ise opolo to fakiki

Ise awon asaraloge ni ki won tunrase. Sugbon nigba mi-in, won tun le baraje. Sebi bise ba se gba ni won se n se e. Ise opolo ni ise tiata, awon onitiata ni won se ise opolo.  Foto: eni ti ...

Read More »

Yanju Adegboyega: Ohun ti won wi ti ko koreeti”

“Nje e mo pe “oye to kan ara Iwo, o n bo wa kan ara Ede, tawon kan maa n wi yen ko koreeti? Ilu kan n be ni ka to de Ede ti won n pe “Awo”, ilu yii ...

Read More »

Wahala sele ni Los Angeles lojo Satide: Rihanna fi komu lasan korin

Lojo Satide to koja yii ni CBS RADIO ranse pe Rihanna, ogbontarigi akorinbirin ile America. Ariya to waye ni Hollywood Bowl to wa ni Los Angeles ni won se lati fi se igbonlongo wi pe awon obirin le segun aisan ...

Read More »

Omoge Onibadi Olokiki Ilu Amerika gbe oyun re rode: Kim Kardashian si ta lenu sibe

Joojumo loyun Kim Kardashian n ga sii. Yato si wi omobirin onibadi olokiki ilu Amerika naa kunra ju ti tele lo, ewa re si wa sibe digbi. Bakan naa ni awon imura re ko fi bee yato si awon aso ...

Read More »

Orisiirisii la n ri nibi eto igbeyawo aye ode oni

Se ara eto igbeyawo ile Yoruba naa ni yii? Oko kawo le aya iyawo re nigba ti iyawo naa kawo le ori (re mi) ololufe re nita gbangba. Se bi won se n se lode oni ni yii? #YorubaDun

Read More »

Iroyin Pajawiri: Olori egbe awon asewo Naijiria, Jessica Elvis ti ku

Iroyin yajo-yajo to sare wole yii lo n salaye wi pe arabirin Jessica Elvis to je olori egbe awon asewo, oninabi ile Naijiria ti rekoja lo sorun.

Read More »

Asiri Tony Blair ati George Bush tu: Blair ti lo toro aforojin ni ti e

Olootu ile Biritiko nigba kan ri, Tony Blair, ti toro aforojin lowo gbogbo aye pelu bose lediapopo mo ijoba ile Amerika eleyii ti George Bush se adari fun lati fogun ja ile Iraq. Alaye yii ni Ogbeni Tony se lori ...

Read More »

Foto: Davido se baba gidi fomo re

Sebi tori omo naa la se n sise… Omoomo baba olowo

Read More »

Won ti yan Ooni tuntun ni Ile-Ife

Awon afobaje ilu Ile-Ife ti yan Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi lati idile Giesi gege bi Ooni tuntun bayii. Won si ti fi oruko oba tuntun naa ranse si gomina ipinle Osun, ogbeni Rauf Aregbesola.

Read More »

Mama o fe e gba: Iyabo Ojo ati omo re

Edumare ma pa omo folomo. Ti eniyan ba ri omo Iyabo Ojo, eniyan le sebi boya aburo re ni. Iya gan-an ni ko si fe gba yii. Oga ju!

Read More »