Gomina Akinwunmi Ambode ti Ipinle Eko gbe ami-eye fun gomina Ipinle Eko ana, Barisita Babatunde Fasola nibi ayeye weje-wemu olodoodun awon amofin ti Ipinle Eko Gomina Akinwunmi Ambode eni to je alejo pataki nibi ayeye ti won pe ni Legal ...
Read More »Demo Blog With Map
Akara Alison-Madueke tu sepo raurau
*O ko sowo olopaa nibi o ti fe fi owo eru ra ile ni London. *Ile ejo gbe ese le owo re mole *Iya re naa ti foju ba ile ejo. *Agbejoro re kede wi pe o ni arun jejere ...
Read More »Iwo taa lo gbeja ninu awon meteeta?
Iwo taa lo gbeja ninu awon meteeta?
Read More »Buruji Kashamu je gbese! Ile ejo ti fagile eto idibo to gbe wole gege bi senator
Ile ejo ti fagile eto idibo to gbe Senator Buruji Kashamu wole sile igbimo asofin agba Abuja lati soju Ogun. Won ni magomago po ninu eto idibo naa, ati wi pe won yoo tun ibo naa di ni.
Read More »Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti
Ebora ilu Owu di Ebora agbaye: Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti Aare ile Naijiria nigba kan ri, Olusegun Aremu Obasanjo baba Iyabo ni won ti yan bayii gege bi siamaanu igbimo egbe ...
Read More »Iwe Iroyin Owuro ose yii kun fofo bi ataare
Ti eyin ko ba tii ra iwe Iroyin Owuro to jade lose yii, a je wi pe iroyin ku sibi kan te e ti gbo. Lati ori oro oselu de amuludun, awon oro to n lo ati igbelaruge asa ati ...
Read More »Ahmed (Amedi) Musa lo rawon julo bayii niluu Russia
Ogbontarigi agbaboolu omo Naijiria, Ahmed Musa, ti n le waju bayii ninu awon agbaboolu to rawon julo niluu Russia. Iroyin yii jade ni kete ti egbe agbaboolu re, CSKA Moscow jawe olubori nigba ti won pade pelu Dynamo pelu ayo ...
Read More »Diezani Alison-Madueke Wo gau! Madaamu Naa Setan Ti O Foju Bale Ejo
Owo awon olopaa ilu London ti te Diezani Alison-Madueke to je minisita fun epo robi nigbakan labe isejoba Goodluck Jonathan. Alison-Madueke ati awon merin kan ni owo te laaro ojo Eti to koja yii pelu esun Jegudujera, riba ati sise ...
Read More »Ara Orisiirisii Nibi Igbeyawo Aye Ode Oni
Iru sitayi wo leyii?
Read More »Ohun to mu Odun Ominira eyi yato si ti igba ti Goodluck Jonathan wa lori oye
Ara opo awon omo Naijiria tun ya gaga si orile ede won lojo Alamisi to koja, nigba ti a se ayeye ominira odun karunlelaadota. Kaakiri awon ipinle, opo eniyan lo ki akegbe won ku oriire, ti won si n soro ...
Read More »