Demo Blog With Map
Se iru ife bayi tun wa?
E ba mi dasi eto yii E dakun Se iru ife bayi tun wa??
Read More »Ta le Feran ju ?
FUNSHO ADEOLU tabi YOMI FASH LANSO
Read More »Moki gbogbo eyin Omo oodua pe asiku imura idibo tinbo yi
Eje kasora dada oledumare koni fi aburu kan wa .ki okunrin merin 4 ki oso eni ti afe ki owa lori aga agba loke loun .ki obirin merin 4 na funwa ni ti won .awon agba ni oun eyan loun oun ...
Read More »Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi !
ORIKI ORILE IREMOGUN:-Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro. Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni. Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon ...
Read More »Esu lalu okiri oko okiri ! (police of the universe)
Esu lalu okiri oko okiri ogo(police of the universe) ako ebo ti ofi orita se afin.Laroye ebora ti ron oju mo omo kinkankinkan. Esu mase mi omo elomi ni kose……….n.
Read More »Oriki Olodumare !
Olubabi Ifaniyi Power
Read More »Oro kan fun odaju abiyamo !
Eku ojumo esinku isimi oni,besini esin tun ku oro ilu, hmm awon yoruba ama paalowe wipe eniyo npanu eni ebinpanranku,Ewo omo tuntun jojolo yi nibi ti wonsonu si ninu poli bagi,sugbon osemilanu wipe omo natidagbere faye bayi ni oni paanu ...
Read More »