Home / Demo Blog With Mappage 34

Demo Blog With Map

Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè.

Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè. Ògbólògbó adigunjalè ní òrò won ti já sí òfo látàrí àì jé kí àwon èèyàn ní ìfòkànbalè ní ìpínlè Delta. Àwon adigunjalè méjì tí ó n ...

Read More »

Babajide Sanwoolu àti Obafemi Hamzat pàdé àwon ìlúmòóká Òsèré.

Babajide Sanwoolu àti Obafemi Hamzat pàdé àwon ìlúmòóká Òsèré. Omo egbé APC tí won yàn láti díje fún ipò Gómìnà ní ìpínlè Eko, tí a mò sí Babajide Sanwoolu àti akegbé rè tí òun a máa jé, Omòwé Obafemi Hamzat ...

Read More »

“Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan.

“Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan. Gbajúgbajà àti ogbóntarìgì olórin tí a mò sí Burna Boy nse ni ó dàbí eni wípé ó ti rí àyànfé, ó pín àwòrán tí ...

Read More »

Cee C jáde pèlú Uriel àti Craze Clown ní Dubai .

Cee C jáde pèlú Uriel àti Craze Clown ní Dubai . Àwon ará ilé BBnaija télè, Cee C àti Uriel ya àwòrán papò pélù Craze Crown ní orílè èdè Dubai. E wo àwòrán àwon àwom métèta tí ó rewà púpò ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé Engineer.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé Engineer. Olúwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tí ó jé Engineer ti pín àwòrán kí ó tó di ojó ...

Read More »

Àwòrán omo odún mókàndínlógún (19) tí won mú pèlú orísirísi èyà ara ní Awka.

Gégé bí ìròyìn se so, won ti fi ìgò gún omo odún mókàndínlógún (19) yánmayànma látàrí àwon èyà ara tí won bá ní owó rè, won bá omoníka àti ojú ara omo odún mérin okùnrin ní Awka, ìpínlè Anambra. Afura ...

Read More »

Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá.

Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá. Gbajúgbajà àti ìlú mòóká òsèré tí a mò sí ìyá ìjo, Tonto Dikeh, ti gbe lo sí orí èro ayélujára Ínsítágírámú láti jé kí ámò wípé nse ...

Read More »

KÁDÀRÁ Ò GBÓÒGÙN

Adáni wáyé ti dáni sáyé ná. Káwayé máyà tó sayé dàwáàlọ. Òréré layé kò see wò tán. Àyàfi ká gba kádàrá lókù. Kádàrá ò seé kọ̀ láìgbà. Ádíá f’ẹ́ja tó f’ibú selé. Ádíá f’ọ́pọ̀lọ́ tó f’òkè s’ebùgbé. Ọ̀pọ̀ló f’omi s’elé, ...

Read More »

Olódùmarè mà tóbi lóba ooo.

Olódùmarè mà tóbi lóba ooo. Kíni olórun olódúmarè kò le se tán, Olódùmarè tó dá ayé òhun òrun tí ó sì so òrò sí órìlè ayé, òrò náà á máa jé Ifá tí ó fi rán òrúnmìlà baba àgbónìrègún. Òdú ...

Read More »

Olorì Basirat tí ó pé odún mókàndínlógún ni ojó mélòó séyìn ya àwon àwòrán tí ó wuyì.

Olorì oba àti ìyá ìbejì ni a gbó wípé ó máa n dá oba lóhùn láàfin àti wípé òhun ni ó máa n pèsè gbogbo nkan tí Kábìèsí fé láàfin àti ní orí èro ayélujára. A gbó wípé kò sí ...

Read More »