Fídíò àti àwòrán àwon òdóbìnrin méjì tí ó ñ jà látàrí òrékúnrin kan ni ó ti gbalè kan . Akékòó ni àwon arábìnrin méjì yí àti wípé akékòó ilé-èkó ifáfitì ti Tai Solarin University Of Education ni won, ìpínlè Ogun, ...
Read More »Demo Blog With Map
Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.
Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè. Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí ...
Read More »Akékòó ilé-èkó gíga tí a mò sí Polytechnic ti ìlú Ede ní ìpínlè Osun ni àwon ará ìlú ti lù pa .
Ní àná ni akékòó ilé-èkó ti poly Ede fi okò pa ènìyàn bíi márùn-ún tí àwon omo tí ó sèsè fé wo ilé-èkó náà pélù okò rè. Bí ó tilè jé wípé, àwon ojú tí ó wà níbè náà so ...
Read More »Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí fi owó rè ra èro ìbánisòrò ní ìpínlè Edo.
Owó àwon agbófinrín ti te arábìnrin kan ní ìpínlè Edo tí ó jé ìyá omo méjì , Miracle Johnson, fún títa omo rè omo òsè méfà tí ó sì di owó náà ra èro ìbánisòrò fún ara rè. Gégé bí ...
Read More »Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn.
Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn. Ìyàlénu ñlá gbáà ni ayeye Àádòrún ojó-ìbí olúbàdàn ti ilè ìbàdàn tí a mò sí Oba Saliu Akanmu Adetunji ní ojó Àìkú. Gómìnà ìjoba ìpínlè Oyo Abiola Ajimobi ...
Read More »Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà .
Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà . Sineto Musiliu Obanikoro tí ó jé adarí àwon olúdábòòbò ti orílè èdè Nìjíríà télè ti lo kí baba wa Oònirìsà tí a mò si àrólé odùduwà ní ìlú ilé-ifè ní ojó mélòó ...
Read More »Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan lára àwon omo ilé BBNaija télè kú.
Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan lára àwon omo ilé BBNaija télè kú. Ará ilé àti lára àwon tí ó figa gbága ní BBNaija rí ni Bisola Aiyeola ...
Read More »Ènìyàn tí ó n gbé inú èkú láti ojó yìí tí a kò mò tí ó n jé lágbájá, àwòrán è rèé.
Okùnrin kan tí ó n gbé inú èkú fohún bí egúngún tí a mò sí lágbájá ni àwòrán hàn ní ìsàlé yí fún ànfààní àwa tí a kò da mò. Gbajúgbajà olórin a kó ni l’ógbón ni Lágbájá àwòrán rè ...
Read More »Favour Iwueze ti Destined kids ti setán láti se ìyàwó.
Omo kékeré àná náà ti dàgbà, àdúrà wa ni wípé kí olórun má pa omo fún olómo. Favour Iwueze ìkan lára àwon omo kékeré ìgbàyan ti setán láti se ìgbéyàwó, kí ire ayò náà kárí.
Read More »Oòni ti ìlú ilé-ifè darapò mó àwon mùsùlúmí ilé-ifè láti kírun ní ojó odún iléyà tí a mò sí Eid-el kabir.
Gégé bí a se mò wípé àwon omo léyìn músùlùmí sèsè se àsekágbá odún won ní léyìn tí won ti gba ààwè séyìn léyìn bí osù mejì àti òsè mélòó sèyìn. Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti darapò mó àwon músúlúmi ...
Read More »