Home / Demo Blog With Mappage 58

Demo Blog With Map

Jude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí Aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè.

Ó ti dá àwon olólùfé won lóhùn lórí èro ayélujára (Instagram), Jude Okoye ti fi ogbón sòrò nípa aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè tí ó sí wípé òun kó ni olórí ebí won. Ó ko síbè wípé. ...

Read More »

Okò tí ó gbé epo petiírólù àti okò èrò ni ó kolu ara won ní Orlu Imo, ogbòn èèyàn ni ó kú.

Ìjàmbá nlá ni ó selè ní orí afárá (bridge) tí ó gbajúgbajà ní Njaba lónà Umuaka – Okwudor ní ìpínlè Imo. Gégé bí ìròyìn se so okò epo petiírólù àti ti gáàsì tí ó kolu bóòsì elérò méjìdínlógún ní Orlu, ...

Read More »

Odóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè River.

Ojó díè séyìn ni won pín ìròyìn burúkú tí ó selè sí omo odún mérìnlélógún yí tí ó jé àgùnbánirò, tí a mò sí Miss Chinda Uchechi Happiness, ni ó pàdánù èmí rè ní ojó kokàndílógún osù kokànlá (November 19) ...

Read More »

Maryam Sanda ti sun ekún àsun-n-dáké nígbà tí won gbe lo sí ilé-ejó látàrí ikú tí ó se pa oko rè Billyaminu Bello.

    Maryam Sanda tí won fi èsùn kàn wípé ó gún oko rè Bilyaminu Bello tí ó jé omo alága egbé PDP télè, Haliru Bello pa ní ilé won ní Abuja ní ojó àìkú (Sunday) tí ó kojá, ni ...

Read More »

Arábìnrin yí se ayeye ojó-ìbí fún omo òdò rè ní àrà òtò.

   Èyin obìnrin n’ílé, èèyàn mélòó ni ó le se eléyìí fún omo òdò rè. Omodé yí àti olówó rè rè é nínú àwòrán yí, àná ni ojó ìbí rè. E jòwó obìnrin mélòó ni ó tún le se èyí ...

Read More »

Àwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won.

Àwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won. Eléyìí ma ti è wuni won sì rewà pèlú oyún won papò. Mo ro wípé oyún kìí mú àwon èlòmíràn rewà ni, bí ti ...

Read More »

Iyabo Ojo dùn nínú aso tí kò bo ìdodo (crop top) tí ó wò.

Ògbó-n-tarìgì òsèré, Iyabo Ojo ti gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti àwòrán ara rè nígbà tí ó ti pé ogójì odún tán , ó sì tún fi hàn wípé dunú. Òsèré Iyabo Ojo, yó se ayeye ogójì (40) ...

Read More »

Gomina Obiano lo kí Ààre Buhari ní Abuja léyìn tí ó gbégbà orókè níbi ètò ìdìbò tí won sèsè dì tán ní Anambra.

Gómìná ti ìpínlè Anambra tuntun, Gómìnà Willie Obiano ní ojó etì (Friday ) ti lo kí Ààre Muhammadu Buhari ní ilé-ìjoba ní ìlú Abuja. Obiano ti dúpé lówó Buhari nítorí kò se àgàbà-n-gebè níbi ètò ìdìbò tí ó kojá ní ...

Read More »

Arábìnrin yí ni ó jí èro ìbánisòrò ogbòn (30) tí ó sì ko pamó sí inú kómú àti pátá rè.

Arábìnrin yí ni ó jí èro ìbánisòrò ogbòn (30) tí ó sì ko pamó sí inú kómú àti pátá rè. Odóbìnrin tí a kò mo eye tí ó su ú, ni ó jí ju èro ìbánisòrò ogbòn lo tí ó ...

Read More »

Nabila Fash kúnlè Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.

Nabila Fash kúnlè Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won. Ìyáwó Oritsefemi, Nabila, wà ní orí ìkúnlè níwájú oko rè nígbà tí ó bá Dólà fun níbi ...

Read More »