Ìgbéyàwó omo Saraki tí ó ti gbòde kan tí àwon òtòkùlú orílè-èdè Nàíjíríà sì péjú pésè níbè. Ay apanílèrín àti Aliko Dangote náà sì lo. Won sì jo ya àwòrán níbi ìgbéyàwó naa….
Read More »Demo Blog With Map
Tinubu, Modu Sheriff, Ben Bruce níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki.
Ní ìsàlé ni àwòrán ayeye ìgbéyàwó omo Saraki tí ó n jé Olutosin Halima Saraki, omobìnrin Saraki, omo asojú ilé-ìgbìmò asòfin , Bukola Saraki tí won se ní ilé ìtura àti ìgbàlejò (Eko hotel and suites ) ìpínlé…
Read More »Omokùnrin Amanda Ebeye se ayeye odún kan ojó ìbí rè.
Ìyá tí inú rè n dùn pín àwòrán òun àti omokúnrin rè sí orí èro ayélujára (Instagram) tí ó sì ko síbè wípé ” kú ayeye ojó ìbí rè omo Mi…..Ayé mi ….Enìkejì mi…. Eni tí ó ...
Read More »Kí le ma se fun tí ó bá jé omo yín lásìkò yí.
Èmi ma le àpótí mo…
Read More »Àwòrán Mompha àti àwon omobìnrin Chinese tí Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá won sùn.
Síwájú Hushpuppi bú òré rè tí ó so wípé kò ní owó lówó lórí èro ayélujára (Instagram). Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá àwon omobìnrin Chinese tí kò to sùn. Àwòrán Mompha re, pèlú àwon ...
Read More »Àwòrán tí Aduni Ade àti omo rè okùnrin yá tí ó sì wuni .
Arewà tí ó bí omokùnrin méji ni ó pín àwòrán òhun àti ìkan lára omo rè méjì sí orí èro ayélujára (Instagram). “Won n bínú wíwà l’áyé wa Tí ó sì jé wípé àwon ni won sún mó ...
Read More »Kàyééfì ò ní yé selè, odóbìnrin kan ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti lógò starboy sí èyìn rè.
Òkan lára àwon olólùfé Wizkid ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti logo starboy sí èyìn rè…
Read More »Asojú ilé-ìgbìmò asòfin Ademola Adeleke, ni a rí tí ó n jó pèlú àwon arewà.
Àwòrán ègbón Davido, asojú ilé-ìgbìmò asòfin ní bi tí ó ti n jó láàrin àwon arewà…
Read More »Opolo arakúnrin yí yanilénu.
Arákùnrin ará Cameroon ni ó fi igi oparun gbé kúlà yí, eléyìí tún ya ni lénu ooo…ogbón kìí pé ní ilé ayé sha…
Read More »Eléyìí tún ya ni lénu ooo! Àwòrán akékòó tí ó pa ara rè.
Ní àárò ojóbò, ojó kerìndílógún osù kèwá, (26/10/2017) ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) àti agbègbè rè pàdánù omo ilé-ìwé kan tí ó n jé Afolarinmi Mercy tí ó wà ní ìpele àkókó (100level) ní eka èkó Micro biology…
Read More »