Home / Demo Blog With Mappage 92

Demo Blog With Map

Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016

Hummmmmm ile eni lati nje ekute oni dodo, Morojo oko re feni kankan mo Tori Kosi bi tise o si oni kaluku naa nfaso bo tie ni wara o si loni, wara nbo lola Woo Orewa Kosokunrin tope nile aiye ...

Read More »

Odu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe…

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a sanwa sire gbogbo o ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Òkan fìkìkìkì babalawo oladeji difa fun oladeji eyiti won nfojojumo njuwe re fun iku, won ni ...

Read More »

Kabiyesi Sango O!!!

Read More »

Yoruba Bo Won Ni Agbomojo Lomo N Moju…

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Ido Alayo ti ose yi. ...

Read More »

Idile Alayo Toni – 17.09.2016 (E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo)

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku aseku odun emi wa yoo se pupo re laye, layo ati ni alafia ara. Mo si ki awa ololufe eto yi, wi pe e ku ...

Read More »

Iyawo re o, a mo eni towu oooo!

Owo idana o po ooo 5,000 pere ni oooooo

Read More »

N je e ran’ti iwe yii?

Read More »

Ijinle Ninu Oro Ifa Fi Ye Wa Nipa Bi Ila Se De Atelewo Wa.

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Ojó oni a san wa o ao ri tiwa se o ase. Gegebi awon opolopo eniyan se maa nsoro wipe “atewolabala ao meni to ko” lotito la ba ila latelewo wa sugbon imo ijinle ...

Read More »

Ifa Iwure Toni Jade Ninu Odu Ifa Ogundigara

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku aseku odun o emin wa yio se pupo re laye awon alaseku yio bawa se o, ako ni rogun inira o ase. Ifa iwure toni jade ninu odu ifa Ogundigara Ifa naa ki ...

Read More »

Eyelé kìí léegun ìsé lára …

Eyelé kìí rìnrìn ìyà l’ésè Eye tó bá ye làá pè l’éyelé. Good morning Universe!!! May the blessing of today abide with each and everyone of us. Ase!!! Popoola Owomide Ifagbenusola

Read More »