| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, gbogbo ojo aye wa yio maa dara si lojojumo ni o ase. Odu ifa IROSUN MEJI ...
Read More »Demo Blog With Map
Odu Ifa Osa Meji
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi opin ose, adura wa yio gba o. Odu ifa OSA MEJI lo gate laaro yi, ifa yi gba akapo ti odu ifa yi ba jade si niyanju wipe ki o sora gidigidi ...
Read More »Ogulutu Oro Toni – 27.08.2016
Hummm bona kan o badi odamiloju pe ona Miran olela,iyen fun enito ba mo nkan ti nse. Woo Orewa Benikan ba sope sise re titan lodo ohun, mofe komope ose tie ni kose ti Olohun o, nise ni kode fila ...
Read More »#Osunisholy
Ologbo se oro okije aresa se oro okije ase ije osun osogbo ni oni yi o emafi osun se ibaje eyin eni yan ibi ema ba olosun je osun ki se ote osun ki se ibaje tori idi eyi olosun ...
Read More »Odu Ifa Ogunda Meji/ Ejioko
| | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana, bi ile oni se mo ao ri tiwa se ise wa yio si ni ibunkun lori ase. Odu ...
Read More »Ifa ni…Mariwo fi’bi faara la ile;
Mariwo fi’bi faara la ile; Awo won ni Ile Ìlalà; A difa fun won ni Ile Ìlalà; Nibi ojumo rere tii mo ni; Ojumo rere lo mo wa loni o. Aase! Ifa says: Mariwo fi’bi faara la ile; The Awo ...
Read More »Odu Ifa Owonrin Meji
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana, eledumare yio pese fun aini wa loni ase. Odu ifa OWONRIN MEJI lo gate laaro ...
Read More »Oríkì Ẹ̀rìn Òsun
Ẹ̀rìn moje ọmọ saaja, Ọmọ eléwé ladogba òróró maro, Ẹ̀rìn wagunwagun Ewá w’Ẹ̀rìn logun eniti yíò wá Ẹ̀rìn logun kowa àpò ide kolowa ọfà, Bàbá kòníbon ajíperin nílé, karo ń lè mọ wọn lójú ogun ẹni Ẹ̀rìn mọ jẹ́ ta ...
Read More »Ìfẹ́ láàárín ara wa
Ìfẹ́ láàrin ara wa Ìfẹ́ dára, Ìfẹ́ dùn bí a bá pàdé oní tí wá, Ìfẹ́ jẹ́ òhun tí ó má ń ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn, Yálà ọkùnrin sí obìnrin, Obìnrin sí ọkùnrin, Ìyá sí ọmọ, Bàbá sí ọmọ, Ọkọ ...
Read More »Ìtẹ́lọ́rùn – #Ìtẹ́lọ́rùnṣepàtàkì.
Ìtẹ́lọ́rùn ni baba ìwà, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe pàtàkì fọ́mọ adamọ, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe kókó, A gbọdọ̀ ni ìtẹ́lọ́rùn, Kí a le rí ayé gbé, Kí a le gbáyé ìrọ̀rùn, Aìní ni ìtẹ́lọ́rùn le mú ni jalè, Bí ohun tí a ni kò ...
Read More »