Demo Blog With Map
Ogulutu Oro Toni 18.08.2016
Hummmmmm ohun ta nfe la ndaso bo koseni tio mope irun ori poju irun ibikan lo woo orewa Nje o mope ohun taba gbe pamo ni I niyi? Moraso ogun mofi han eyan ogbon hummmmmm. gbomi dada Bisu eni bata ...
Read More »Odu Ifa Owonrin Elejigbo/ Otua
| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku imura toni, mo gbaladura wipe bi a se njade lo laaro yi aori ...
Read More »Odu Owonrin Alakuko/Irete
| | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku imura toni o, mo gbaladura laaro yi wipe eledumare yio mu gbogbo nkan to ndena ...
Read More »Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se!
A ku imura! Awo Alaseye! Isese o, o ti d’ogererere! Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se! Aase! K – Awodiran Agboola IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »Orisa Alaase, Igbakeji Olodumare
Odu Ifa Owonrin Alakara/ Ika
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku isimi alayo loni eledumare yio funwa ni isimi to peye ...
Read More »Oruko kan fu foto yi ?
Oruko kan fu awon arakurin yii ?
Read More »Aja To Rele Ekun To Bo..
Aja ti o ba rele ekun ti o si pada lai f’arapa ti iru aja be o si le gbegba ope olowo aja be ni yoo fi se ounje ajesun laipe ojo. KABIYESI ILU MOYE ni a o ba maa ...
Read More »Oriki Ibeji
Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, ...
Read More »