| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa ...
Read More »Demo Blog With Map
#CelebratingOsun
Ladekoju Oore Yeye Osun o! E ku odun o! Osun Sengese Oyeyenimo a gbe wa o! Aase! Photo Cc – Bekky Amusa
Read More »Odu Ifa Owonrin Tutu/ Oturupon
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio gbo adura wa o yio si bawa tu ile aye to ...
Read More »“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo….
“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo Wun ó bí’mo lé’mo n tó máalo Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo Bí Wón n n’íre lórun èmi ò mò Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo I will have enough ...
Read More »Egbo talo daran egbaafa ninu awon mejeji ?
Alabahun (ijapa) lo re ile ana re oni ohun le so epa mefa di egbaafa ki odun to yipo, alabahun gbin epa tan ikun de’be o wu epa je ni ijapa ba ni ikun ti daran egbaafa. Ibeere talo daran ...
Read More »Ogulutu Oro Toni – 09.08.2016
Hummmmmm onilari koseda tomola #woo_orewa Bo ba ndara fun o loni mase fi omolakeji re se yeye Mofe koranti pe kise agbara re ni ipo towa loni #gbomi_dada Iyanju lagbe ngba obami oke lo nmusu(yam) ta, bi agbara ba nbe ...
Read More »Odu Ifa Owonrin Okanran
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin tu ku imura toni, aku isimi opin ose emin wa yio se ...
Read More »Òró gangan la nba Òsùn.
A ku Ose Sango!
Owonrin Odi I II II II II I I I Owonrin sindin sapere Adifafun Bata abufun Sango nijo won torun bowaye ebo won ni kiwon ose awon mejeji gbebo won sisebo Bata ni owonrin sindin sapere Sango ani okuu temi ...
Read More »Happy Isese Day (August 20th) in advance!
Iba Olodumare Iba Ifa Olokun Asorodayo Iba Obatala Oseeremagbo Iba gbogbo Irunmole Isese Day yio ba wa layo! Aase! Happy Isese Day (August 20th) in advance!
Read More »