Home / Àṣà Oòduà / Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se!

Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se!

A ku imura!
Awo Alaseye!
Isese o, o ti d’ogererere!
Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se!
Aase!

 

K – Awodiran Agboola

  • IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo