Arábìnrin tí ó jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) tí a mo orúko rè sí Caramella Mou ní won fi èsùn kàn ní órí èro ayárabíàsá látàrí wípé ó wàású fún arákùnrin awakò kan tí ó jé mùsùlùmí ...
Read More »“Èmi ni mo ni é” Adesua Etomi ni ó sobéè fún Banky W nígbà tí ó pín àwòrán ìgbéyàwó won.
Àrídájú ti wà báyìí wípé Adesua Etomi àti Banky W ti di tokotayà, gbajúgbajà òsèré bìnrin ni ó sèsè pín àwòrán won yí tí ó sì so irú ìfé tí ó ní fun, nse ni ó dàbí eni wípé ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó ti arábìnrin tí ó tóbi àti oko aràrá.
Nígbà tí mo rí àwòrán yí ní orí èro ayélujára , mo kókó dúró ná mo wá bi ara mi ní ìbéèrè wípé kíni obìnrin fé nínú ìgbéyàwó tàbí lára okùnrin ? Léyìn òpò ìrònú àti òpò ìrírí ...
Read More »E wo aso Ebuka níbi ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti ìyàwó rè, Adesua Etomi.
Òpò ni ara ti n yá tí won sì ti fi ojú s’ónà láti wo aso tí Ebuka ma wò ní òtè yí báwo ni ó ti è se ma rí nínú rè ni ìbéèrè àwon ènìyàn, bí ó tilè ...
Read More »Àwòrán ìsìnkú Akékòó jáde ti ilé èkó gíga Nnamdi Azkiwe (UNIZIK) tí ó kú ní òsè mélòó séyìn.
Olóògbé Arábìnrin Amaka Ezeokoli tí ó kú ní òsè mélòó séyìn léyìn àìsàn péréte , se ni won ti sin-ín ní ojó Àbáméta (Saturday) ní ìlú tí won bi sí ní Ezioko ní ìjoba ìbílè Gúúsù ti Orumba tí ó ...
Read More »Banky W àti Adesua Etomi fi enu ko ara won lénu níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè won ní orílè èdè South Africa .
” O le wá fi enu ko ìyàwó lénu báyìí” ni ó ma n dùn jù nínú ìgbéyàwó, tí kò bá rí béè Banky W àti Adesua kò bá má se tó báyìí, won ti fi enu ko ara lénu ...
Read More »Ìsìnkú àwon tí won kú níbi ìjàmbá okò tí ó selè láìpé ní ìpínlè Imo.
Gégé bí Holychidi Ojlkorie, ìgbákejì olùgba oko àti aya n’ímòràn ti ìjoba ní ìpínlè Imo télè, òpò ènìyàn bí ogbòn ni won kú níbi ìjàmbá burúkú tí ó selè láìpé láàrin glokò epo petiróòlù àti okò èrò elérò méjìdínlógún (18) ...
Read More »Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won.
Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won. Tokotayà tuntun, Banky W àti Adesua Etomi pèlú ègbón Adesua Etomi okùnrin, ìyá rè àti àwon òbí oko ní apá òtún èyí ma tún dára ...
Read More »Banky W àti òré tímótímó tí ó rè le lo gba ìyàwó rè ( Adesua Etomi), Tunde Demuren .
Banky W àti òré tímótímó tí ó rè le lo gba ìyàwó rè ( Adesua Etomi), Tunde Demuren . Banky W àti òré rè tímótímó fún ìgbéyàwó alárédè rè, Tunde Demuren ni won Jo ya àwòrán papò níbi ìgbéyàwó alárinrin ni ...
Read More »Oritsefemi dòbálè ní iwájú àwon àna rè, àwon òbí Nabila Fash níbi ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.
Oritsefemi àti àwon òré rè ti dòbálè níwájú àwon ebí ìyàwó rè tí a mò sí àna rè níbi ìgbéyàwó náà, ìgbéyàwó náà dára púpò. N se ni ó dàbí kí èmi náà lo se ìgbéyàwó báyìí.
Read More »